ORIN TI ÒSÒGÌNYÓN
Eèpàà bàbá (grande admiração pela honrosa presença pai)
Òrìsànlá
Òrìsà òkè nínu won gbogbo òrìsà! (Orixa acima de todos os Òrìsá )
(ILU)
Ajagùnnòn àgbà awo Ajagùnnòn.
Ajagùnnòn bàbá ó Ajagùnnón.
Elé mò ojó oba wa olóroògùn,
Ajagùnnòn bàbá ó
************************
È è è bàbá
Bàbá k opa bi òsògìnyón
Ìgbín òòsààlà ke pa
************************
Òsògìnyón ti bi
Òsògìnyón ti bi olè
************************
Ajagùnnòn biti e
Ajagùnnòn biti ode
************************
Ajagùnnòn bitiko
Ajagùnnòn bitinmole
************************
Ala forikan meje kuo
Ala forikan imole
************************
aka ka ka un'bo, ko ko ooo
aka ka ka un'bo, ko ko ooo
*
aka ka ka un'bo, biti ode
aka ka ka un'bo, biti ode
************************
Ko pa re re
Baba e ko pa re re si
Ko pa re re
Baba e ko pa re re si
************************
A un'bo, a un'bo lo'wo, a un'bo
A to ko de
A un'bo, a un'bo lo'wo, a un'bo
A to ko de
************************
Ojoo ìgbín erò oye
Bi ero bi ero
************************
Orisá oko bi ero ode
Bi ero bi ero
************************
Ipê funfun, ipê ri mode
Ipê ripe o
************************
Orisa danko bi ero ire
Bi ero bi ero
************************
Awa sooro awa soro ile
Olori pe o
Awa sooro awa soro ile
Olori pe o
************************
Awa jun si awa jun si t’ogun
Olori pe o
Awa jun si awa jun si t’ogun
Olori pe o
************************
Awa axo, awa axo i baba
Olori pe o
Awa axo, awa axo i baba
Olori pe o
************************
Olori pe o
awa axo in olori pe
Olori pe o
awa axo in olori pe
************************
E pan ka la
E pan ka la
A ina akoro pan ka la
E Pan ka la
************************
Awa junsin awa junsin t’ogun
Sooro Sooro
Awa junsin awa junsin t’ogun
Sooro Sooro
************************
A ina ko ro la pe wo
ko ro la pe wo, ko ro la pe wo
A ina ko ro la pe wo
ko ro la pe wo
************************
Ala ipe o
Ala ipe ipe ala
Ala ipe o
Ala ipe ipe ala
************************
A un sooro, a un sooro fe igbin
Awa in o sooro fe igbin
un sooro fe igbin
Awa in o sooro fe igbin
************************
(EGO)
Awa sooro mele rin
Òrìsá oko sooro fé in sin
************************
Sooro mele rin
Omoro ko soro fe in sin
************************
Barere ke mi barere
Abuke ke mi barere sin
************************
Kun barere kun barere sin
kun barere
************************
Bàbá e ire baba
Bàbá ko gba osogiyan
Orinsala ke epa
A ka ka un bó
O ku o
************************
(KORIN EWE)
Olua mi ikeke o
Orisaoyion legibo, legigbo Ajagunan
Olorun agbe be teru le
Olorun agbe be teru le
Olorun agbe be teru le
Olorun agbe be teru le
************************
Maa kan se, maa kan se
Baba eèpàà èé
Maa kan se, maa kan se
Baba eèpàà èé
************************
Òfuurufú e aláayé ó Àjàlá
bàbá ki yíyè yè Elééjìgbò.
Ilè iré ki ojú e bàbá
Èjìgbó rè e mo júbà awo Olúwa mi,
E mò awo, E mò awo, Baba eèpàà èé!
Elémòwo Eléèjiìgbò.
E mò awo, E mò awo, Baba eèpàà èé!
Elémòwo àwa okòn,
E mò awo, E mò awo, Baba eèpàà èé!
************************
A ko ro ko ro ko de
Baba eèpàà èé
A ko ro ko ro ko de
Baba eèpàà èé
************************
Àwa dé o mo ji bí ó,
Àwa dé o mo bò'jú rè lé.
Bàbá ki ìbá àsé ó
Àwa de o mo bò'jú rè lé bàbá
************************
Maa bo se, maabo se
Baba ebo maa bo se
Maa bo se, maabo se
Baba ebo maa bo se
************************
Òfuurufú, òfuurufú, òfuurufú. Bàbá òde, bàbá òde, bàbá òde
Òfuurufú, òfuurufú, òfuurufú. Bàbá òde, bàbá òde, bàbá òde
************************
Òfuurufú, fuufú, fuufú
bàbá òde
************************
Mèrò yìn mèrò yín,
Bàbá èyin e mó awo
************************
Elé bàbá bèrè kíì ó,
E mò awo
************************
Àwa dé o mo tí bí ibí ó,
àwa dé o mo ti bí bàbá.
Bàbá ó a dé ó,
àwa dé o mo ti bí bàbá
************************
Elé bàbá bèrè kíì ó,
E mò awo
************************
ORIN TI ÒÒSÀÀLÀ
Eèpàà bàbá,
Òrìsànlá,
Òrìsà òkè nínu won gbogbo òrìsà! Eèpàà bàbá!
(BATA)
Oní sé a àwúre a nlá jé.
Oní sé a àwúre ó bérì omon,
Oní sé a àwúre,
A nlá jé, Bàbá.
Oní sé a àwúre ó bérì omon
************************
Eni fé waó orò olúwa odó,
Eni fé wa oró olúwa odó,
Eni fé wa oró ó bérí omon
Eni fé wa oró,
************************
Ojo ní bí won ni bò oore o
Elé komo Òrìsà siré
Ojo ní bí won ni bò oore o
Elé komo Òrìsà siré
************************
A e a e agan
Agan mado Òrìxà
A e a e agan
Agan mado Bàbá
************************
(ÌGBÍN)
Àjàlá mo rí mo rí mo yo
Álá forí kòn
E àgó fi rí mi
************************
Bée orí kò kíì Àjàlá
bàbá òkè
kí a mò rè. Kíì Àjàlá,
bée orí kò
************************
Epo kété ó,
Àlà tekè ó
************************
Ó pèré kété
Ó pèré kété bàbá,
Igbá ó ní. Alà kò ìjeníìya àwa,
Ó pèré kété bàbá
************************
Òrìsà réwà
Mo r'a bàbá èé,
Mo r'a bàbá nílé wa ó.
Mo r'a bàbá èpàà! Èé!
************************
Àwa bàbá kí ilé wa awo,
Àwa bàbá ní eèpàà! Èè!
Òrìsá e réwà,
Àwa bàbá ní eèpàà èé
************************
Àsò funfun àwa bí (ó wá bí)
Àsò funfun. Ti Òrìsànlá,
Aláayé Àjàlá ó
Àsò funfun ti Òrìsànlá
************************
Àlà funfun àwa bí (ó wá bí)
Àlà funfun. Ti Òrìsànlá,
Aláayé Àjàlá ó
Àlà funfun ti Òrìsànlá
************************
Òwú sílè ìgbín e tòróró,
Bàbá á fé àbá (àgbà).
Kí e mò awo
************************
Èyin a komo dèngé oore
Èyin a komo
************************
Ègbo bàbá ègbo nje àwa
Ègbo bàbá ègbo nje àwa.
Òrìsà s'a àlà bòrì ó,
Ègbó
bàbá ègbo nje àwa
Ègbó
bàbá ègbo nje àwa
Ègbó
bàbá ègbo nje àwa
************************
Èyin rí àwa
Ìgbàgbó wa okòn
Èyin rí àwa.
Ìgbàgbó wa okòn
Ki ri lu ki ipàdè siré
Bàbá eèpàà
************************
Èyin rí àwa
Ìgbàgbó wa okòn
Èyin rí àwa.
Ìgbàgbó wa okòn,
Ètùtù sé ipàdè siré,
Kò rú lé.
Kò rú lé bàbá Ifá,
Kò rú lé kò rú lé bàbá Ifá.
Kò rú lé ò rú lé bàbá. Ifá
Kò rú lé kò rú lé bàbá Ifá
************************
Àkàkà ngbà a e bàbá
Àkàkà ngbà a e bàbá
************************
Bàbá burukan burukan
Bàbá burukan abi etu
Bàbá burukan bi ile
Bàbá burukan e yawo a e
************************
Aye oba la we ge
Oba la we ge
Bàbá fun mi laye
Oba la we ge
************************
A e Danko a da gue mare
A e Danko
A e Danko a da gue mare osalufon
A e Danko
************************
Àgó Àlà, Àlà Ofun
Osú te ke re
************************
(IJESA)
Olóòrun a kíì ìbá àse ó,
E bàbá oní
************************
Ó fí là aláyé ó iré ilé àwa.
E bàbá a àwúre ó iré ilé àwa
************************
Ó dúró, ó dúró oní àlà
E mòn mòn ojó Òsògìnyón.
E ní mòn mòn ojo Òsògìnyón
E ní mòn mòn ojó Osólúfón
************************
Èrò, bàbá mi sérò,
Èrò mi bàbá kòjáàde
************************
Aráayé bàbá njéé-jèè,
Bàbá mo rí ó
Aráayé bàbá njéé-jèè,
Bàbá mo rí ó
************************
É mi ire mi ire
É mi ire mi ire
Bàbá Olóòrun, bàbá mo ri e.
Àgbà odó àlà sorí àwa ó
************************
Ni òrun ó oní re mi dé,
Bàbá mo dúró
************************
Bàbá òkè
Eèpàà! Eèpàà! Olóodoó,
Bàbá òkè
************************
Ojo mò tyìn odó aláyé ojó,
Ojó bí walé ojó.
Ojo mò tyìn odó aláyé ojó,
A bo wa bàbá ó
************************
É é mo rí ó é mo rí Ifá ó
É é mo rí ó é mo rí Ifá ó
************************
A ire a ire bàrá a ire,
A ire bàbá
************************
Àwa aláyé é é,
Bàbá nlá eèpàà èé
Àwa aláyé é é,
Bàbá nlá eèpàà èé
************************
Eyíyè ní Ifá èrò
E yíyè ní ifá èrò,
Òòsààlà. Kíì ó mo sàké,
Òòsààlà ki àwa wúre,
É Òòsààlà. Kójáàde ó
************************
Àwúre ó bàbá ki a fé e jòwó
A àwúre ó. Bàbá ki a fé èyin, Ènyin a pè
E Irúnmonlè.
Ènyin a pè
E Irúnmonlè
************************
Àlà à ó àlà orò àlà
Eèpàà bàbá.
Àlà ó àlà orò àlà
Eèpàà bàbà
************************
Àwa fún kín-kín ó àlà,
Bàbá àwa àwúre.
Àwa fún kín-kín ó àlà,
Bàbá àwa àwúre
************************
Àlà ki kójáà mi dé,
Àlà ki kójáà mi dé.
Àwa bo Obàtálà
Àlà ki kójáà mi dé
************************
Òrìsà gbè mi,
Bàbá mi olóòde
Òrun wa bábà,
Bàbá ibi, bàbá ibi ó dé
************************
(Mandar embora)
Òrìsà oore, Òrìsà oore à nló.
A l'anu re àjò
************************
(Mandar embora)
Bàbá mi nló
Bàbá òrisá sirè lo dé
************************
(BATA)
Odùduwà rè óó
A júu mà olòjò
Odùduwà rè óó
A júu mà olòjò, Olúwáiyé
************************
E lé péré niwa pá la ó
Olojo máa máa, ilè wa lù mà
E lé péré niwa pá la ó
Olojo máa máa
************************
Àwúre wa Òrìsá ,
Gbe nu gbe wo gbe wo
Gba sè wa óóó
************************
Orixá te nun bo
Te nun bo, te nun bo
************************