(AGUERE)
Awòn orisa ode lokoN’ofà akueranOde nise we re lokoN’ofà akueran e
Oní aráayéOde a rere òkè Àwa orisa erò.Orun ofà akueran*********************Olówó gìrì-gìrì lóòde, Ó gìrì-gìrì lóòde. Ó wà nígbó òrò ode òkè ó dára sáà ló gbéeron*********************Lo kwe re, Lo kwe reOde olorokeLo kwe re, Ode loko wa yeLo kwe re, Ode oloroke*********************Òsì igbódé E òsì igbódé Àárò lé òsì igbodé. E òsì igbódé*********************Aró lé o si imonlè ki wa jóAró lé o si imonlè ki wa jóOní ará ayé Eero si imonlè ki wa jó. *********************Ode ki omò’ro Odé Ode ki omò’ro Odé, Ode a re re. Ode ki omò’ro Odé ní mawo, Ode ki omò’ro Odé oníye*********************Àgògbó layeAre le àgògbó (Oni la Ase)*********************Àgògbó mi ìro, lesé mi oró, Òró imonlèÀgògbó mi ìro, lesé mi oró, Òró imonlè*********************Ofà rè ye ye figbó Odé fígbó. Ofà rè ye ye ko sè Omorode*********************Ewá tirè òkè, Ewà tirè ní lé igbbó rè ó*********************K'òkè ké-ké k'òkè ode, Òkè ó k'òkè ode*********************I, a jo k’ofa ri a odeI, a jo k’ofa ri a ode*********************O lè lè koke i a odeO lè lè koke i a ode*********************Ode sí Odé , káre rere Káre Odé rereOde sí Odé , káre rere Káre Odé rere*********************Ará wa won ní je ki ofà rè won, Ará wa won ní je ki ofà rè won,
Àgò ofà ni won a Aró ilé kódé wa jó níigbó ó,
Ará wa won ni je ki ofà rè wonArá wa won ni je ki ofà rè won*********************Bi ewé, Bi ewé bàbá
Àrólé bi ewé, Àrólé bi ewé, bàbá. Àrólé bi ewé, Àrólé bi ewé, bàbá.*********************A legi bo, A legi bo gboro
Oni loju boOni loju bo gboro*********************Arole komurajo ...E un fe le, e un páArole komurajo ...E un fe le, e un pá*********************Arole Ipeja odo, aroleArole Ipeja odo, aroleArole Ipeja odo, aroleArole Ipeja odo, arole*********************Odé Kare, Odé Karele OdéOde fi Odé KareleOdé Kare, Odé Karele OdéOde fi Odé Karele*********************E ma wo ireE ma wo irePe ni kuo kuoAse guere guede, iya ode, oni è *********************Otin re, le le OtinA le le ba reOtin re, le le OtinA le le ba re *********************Ofa emi Ode piriaPiriá, piriá, piriá*********************Irinle, Irinle o, Osi OrileIrinle, Irinle o, Osi OrileBaba Akueran, Osi OrileOde Kare, Osi OrileBaba Ysanbo, Osi Orile******************************************Ó Dánón Dánón ti sè eron ode. Gìrì-gìrì lóòde ode ní ó*********************E ló kèrè Ode àárò lé ló kèrè. Ode àárò lé ló gbè wa E ló gbè wa*********************Olúwàiyé wà rere àgògbó, Olúwàiyé àgògbó*********************Omorode sè rè ewé irokò, Sè rè ewà ló igbó.
Oní aráayé ode a rere ó pè omorode sè rè ewé. Ìrokò Sè rè ewà ló igbó********************* Ode dudu e du a be tanOde dudu e du a be tan*********************Ode dudu awa ma o raOde dudu awa ma o ra*********************(ILU)
O si onile Akaro si lé igbo akueranO si onile Akaro si lé igbo akueran*********************Ni Ode pe mi oNi Ode pe mi oNi Ode ogun nhã nhãNi Ode pe mi o*********************Omorode ko sì le arole àgó ni faOmorode ko sì le arole àgó ni faKóíía Kóíía ko sì learole àgó ni fa*********************Omorode uni uniOmorode uni uniE uni uni, Odé YbainOmorode ki sajo*********************Omorode e e eOmorode ki sá joOmorode e e eOmorode ki sá jo*********************Okuo ode labureOkuo ode labureBa in’lá lo já guiri le ode Okuo okuo ode *********************Ara ni sa, Ode ni sá Ka ku ode kurajoAra ni sa, Ode ni sá Ka ku ode kurajo*********************Orun bo AroleOrun bo Ode lonanOrun bo ara ke sajoOrun bo Ode Lonan *********************Opà okà bèrù jà.Opà okà bèrù jà.Opà okà bèrù jà LononOpà okà bèrù jà Oke*********************Kini kini iya OdeOde pa me kurajo
(ADAHUN)
Kini kini iya OdeA ode nu pê pê*********************Mo bo isè isè ìrokò Mààbò wa, Mo bo isè isè ìrokò Mààbò wa, *********************Kini, kini bo se Mààbò wa, Máàbò wa Loko*********************Bo ro síírí bo sè Mààbò wa, Máàbò wa Loko*********************Omorode láé-láé Omorode ki wa jó. Abà wa bo l'oko kò igbó,Omorode olúwàiyé*********************Omorode l'oní, Omorode olúwàiyé*********************Ó ìdáró Ó ìdáró ìrúnmonlè, Ó idáró lé se mi roÓ ìdáró ìrúnmonlè,
Ó idáró lé se mi roÓ ìdáró ìrúnmonlè, *********************Ó ní iwo níiwo, Bèrù bèrù bèrù*********************Olu guiri lokoOlu guiri lokoOdé o, Odé lonanOlu guiri loko*********************Alaketu wure F’ara imoraF’ara imora oluwoF’ara imora*********************Ode in ode ta-faMa un a unOde in ode ta-faMa un a un*********************jan jan ba inleInle ma da gan ba inle*********************Sire, sireOde Mata Oke Oke*********************Jam bele ke, iroroOde ma ta ko lo jamJam bele ke, iroroOde ma ta ko lo jam*********************Siré, siré Odé Ma ta Oke OkeSiré, siré Odé Ma ta Oke Oke*********************Sa r’Ewa Odé tàfàSa r’Ewa Odé tàfàSa r’Ewa Odé tàfàSa r’Ewa Odé tàfà*********************Àwa tàfà rode, Àwa tàfà-tàfà odeÀwa ará ayé, Àwa tàfà-tàfà awo. *********************Àwa ará ayéÀwa tàfà-tàfà eranÀwa tàfà rode, Àwa tàfà-tàfà awo. *********************Àwa ará ayéÀwa tàfà-tàfà ibynÀwa tàfà rode, Àwa tàfà-tàfà awo. *********************Àwa ará ayéÀwa tàfà-tàfà AiyraÀwa tàfà rode, Àwa tàfà-tàfà awo. *********************Tere mi tere mi tàfà odeTere mi tere mi tàfà awo*********************Ode kini fa la ode kini,Ode kini si luoOde kini fa la ode kini,Ode kini si luo*********************(HUNTO)
Odé bi ewe, Dan a Odé bi ewe,
Dan a dan ode bi ewe************************(ALUJA)
A oyo a egbeOde tàfà sabura, a oyo a ebe*********************E kole mo d’agoE kole mo d’ago léE kole mo d’agoE kole mo d’ago lé*********************Ode o aeOde o ae*********************Ode o aeOde farà pa dè*********************Awo, Awo, Awo, Ode N'ile waOde ki ti fu*********************Ode Gbáà yìí l’àsè A insè bì wa rééOde Gbáà yìí l’àsè A insè bì wa réé*********************Ode ba miráBami ro*********************Singuele arole Singuele ko keSinguele arole Singuele ko ke*********************(BATA)
Omo wureOmo wureAlaketu nù gbeIgbo nù kè ba réréNì bò nù ke lo ni E Alak,,etu re Alaketu nù obo*********************Éró ti tó ayeAwa de le a oioÉró ti tó aye awa de Awa de le a oio oniê************************(HAMUNHA)
Oke Bàbá OkeAlaketu kàáboOke Bàbá OkeAlaketu kàábo*********************(ILU)
O sí e da n’lo, a ko ro paArolé o ko mura jo*********************(cantiga para subir)
Pè kù oPè ku lè pèPè kù o pè kù oPè ku lè pè***************************************************************
Omorode Ode ní ó àjà fún lé léOmorode Ode ní ó àjà fún lé lé*********************Bambo rẹ kẹ tẹBambo rẹ kete owoBambo rẹ kete Bambo rẹ kẹ tẹ owo*********************Omorode ló ìjeníiyàOlúwàiyé. Omorode ló ìjeníiyàOde kòkè*********************Ode koke re wa joO fi o akaka, Ode ko ke wa lejoO fi o akaka*********************Mi Ode pe mi oMi Ode pe mi oMi Ode o ku nha nhaMi Ode pe mi o*********************Pá Odé nu pendekini kini a OdéPá Odé nu pendekini kini a Odé*********************Ofààmi ló sé Ààbò wa, Ààbò wa Aláààbò*********************Pá Odé nu pendekini kini a OdéPá Odé nu pendekini kini a Odé*********************Ipa la Odé paOdé Ma taIpa la Odé paOdé Ma ta*********************
Omorode omo gui gui Ero nan de Omorode omo gui gui Ero nan de *********************