ORIN TI OGUN
Pà ta ko ri ògún
(ògún guerreiro toma conta de suas terras)
Ògún je si je si
(ògún, nos sustente)
Ògún ieé!!
(Salve Ogum)
(ILU)
Ògún àjò e mònriwò,
Alákòró àjò e mònriwò
Ògún pa lè pa lóònòn
Ògún àjò e mònriwò
Elé ki fí èjè wè.
*********************
Àwa nsiré ògún ó,
Èrù jojo
Àwa nsiré ògún ó,
Èrù jojo. Èrù njéjé
*********************
Ògún nítà ewé rè,
Ògún nítà ewé rè
Ba òsóòsí l’oko ri náà lóòde
Ògún nítà ewé rè
*********************
Ògún masa akoro iyawo
Ògún masa akoro iyawo
*********************
(ADAHUN)
Alákòró elénun
Alákòró elénun ó
Ae ae ae
Alákòró elénun ó
*********************
Pa l’ògún méje iré,
Aláàda méji, méji
*********************
Ja re ja re ja ògún o
E ògún wa o ògún gbale
*********************
Jà pè lé, Jà pè lé Jà
Alákòró oníré
*********************
E mònriwò l’aso
E mònriwò
E mònriwò l’aso
E mònriwò
*********************
Àkòró gbà àgádá,
Àkòró gbà àgádá
Ògún gbà àgádá é
Ògún gbà àgádá
*********************
Ògún a kò fíríì,
Ògún a kò fíríì
A pàdé l’ònòn kí a wò, ògún a kò fíríì.
*********************
Oní kòtò, oní kòtò n’ilé ògún
Ó ní àwa ajàjà, oní kòtò ó pa òbe.
*********************
Ògún ní kòtò gbálé o
Mònriwò, àwúre
Ògún ní kòtò gbálé
Mònriwò, àwúre.
*********************
Oní kòtò
Oní kòtò nilé ògún
Àwúre dùró do onìjà, àwúre.
Dúró do.
*********************
A imòn nilé a imòn e
Dàgòlóònòn kó yá
A imòn nilé a imòn e
Dàgòlóònòn kó yá
*********************
Mabe ògún araye
Mabe ògún sooro
Mabe ògún sooro
Mabe ògún sooro
*********************
Akaja loni ogun masa
oke berunjá
akaja ogun masa
oke berunjá
*********************
E awa de lode, ko ro un belé
Akóró ògúnjá, ko ró un belé
E awa de lode, ko ro un belé
Akóró ògúnjá, ko ró un belé
*********************
Ògún pá
lê lê pá
koro pá
Ojare
*********************
Ke kin kin alakoro
ke kin kin alakoro
Oluwaye nilé ògún, Ákòró oníré
Oluwaye zan zan
Ákòró oníré,
Oluwaye zan zan
*********************
Akoro okode
Akoro okode
Fará ògún meje akoro okode
Fará ògún meje ògún fara onire
*********************
Ògún onire
Ákòró onire ore gede
S’ala re
Ògún onire ore gede
Ògún onire ore ko murajo
Ákòró onire ore gede o
*********************
Ògún alakoro so kobo
mariwo lara wé
Ògún alakoro so kobo
Mariwo lara wé
*********************
Ògún to
ògún torode
aja un gbele
opa osi osi ògúnjá
aja un gbele o
*********************
Ògún onire eran godo
abe nu sa
akoro onire eran godo
be nu sa rin
*********************
Awa n'ile o, Ogum mariwo
Awa n'ile o, Ogum mariwo
Ina koro de
Ina koro mariwo (Ogun de baba)
*********************
Mo fo ri loko, mo fori gbale
Mo fo ri loko, mo fori gbale,
Ogum ma le pwe
Mo fo ri loko, mo fori gbale
Ago mo ju ba
*********************
(KORIN EWE)
Ògún onire
Onire ògún
Alákòró onire
Oba de l’ògún
*********************
Ògún de are re
Ire ire ògúnja
Akóró a de a rere
Ire ire ògún ja o
*********************
Ògún de alagbede
Mònriwò odé, ode mònriwò
*********************
Ala da meji osi mole
Fi eje we alákòró
Apa de o ni bi i já
Onire ògúnja o
Ògún de are re
Ire ire ògúnja
A mo pwe àgò l’ònòn
Ko ibi aja le o
*********************
E omo awo a made
A nbele ki awo
Awo a fun àgò l’ònòn
Onire ògúnja o
Ògún de are re
Ire ire ògúnja
Akóró a de a rere
Ile ile ògún ja o
*********************
E oni bo de orun o
E oni bo de orun o
Ni o la la, ni o la ala
E mònriwò
*********************
Ògún ko laso
E mònriwò oná
Ògún ko laso
E mònriwò
*********************
(AGABI)
Ògún se kó re nde
Se kó re
Ògún se kó re nde
Se kó re
*********************
Ina koro sire idan
ina koro sire idan
*********************
É nu kuri á
É nu kuri an de
*********************
A w’ala si tu pá
Méji, méji ògún
*********************
(HAMUNHA)
Maaru le posi da kaya
Maaru le posi na do
Pa zue maaru le posi nado
*********************
Ògún a lakaye a nana ja iná we
Fere a pepe nana ja ra iná were
Fere a pepe nana ja ra iná were
*********************
Eru já olo’ná de
Eru já olo’ná de
Ògún ákòró ki e ja
*********************
Kat akata òbí meje
Òbí meje ònà gbo gbo
*********************
Ògún se ko re
Ta ni loci lode
Ògún se ko re
Ta ni loci oná
*********************
Pa ni ògún ke ma ra wara
Pa ni ògún ke mara o
*********************
Awo de in
A woro ni ògún jaja
*********************
Pa ni obe
E pa ni obe
*********************
Epó ni obe
Epó nu o
*********************
(IJESA)
Ogum mege, Ogun mege
Ogum mege, Ogun mege
Ogum ara mi ba isa
Ogun ni k’ore adabi
*********************
Ogum e pa, baba ogum
Ori l’oyo
A p’ere ogum
Ori l’oyo
Olodo, se mi se mi
Eee a um guele
Ara oro, ara oro
*********************
Ogum po ile ara e
E ibede a ara e
Ogum po ile ara e
E ibede a ara e
*********************
(ILU), vira paara (ADAHUN)
(Cantiga para ir embora)
Da un’lo lo lo lo
Da un’lo le in
Ke mi sale, koja odo
Oba de om ore fi to