ORIN TI YEMONJA
Èérú íyá! – (mãe das espumas da águas! )
Odò ìyá! (Mãe do rio)
Odò fè ìyába! (Amada senhora do rio)
(BATA)
Àwa ààbò a yó
Yemonja àwa ààbò a yó. Yemonja
************************
Ìyáàgbà ó dé ire sé
A kíì é yemonja.
A koko pè ilé gbè a ó yó
Ó fí a sà. Wè rè ó
************************
À sà wè lé,
A sà wè lé ó odò fí ó
A sà wè lé
************************
Ìyá kòròba
Ó kòròba ní sábà
************************
Ori ó
N’ilé iya òyò
Iyemanja ori ò n’ilé
Iya ori
************************
À òyò, iya de lò dè ó ó
Yemanja ogun
Ogun pá ààjà ré iya òyò
Be tè lo èjè
Iyemanja ogun
A òyò ori lé
************************
Ma rele àwa ààbò sá renà
A oyo àwa ààbò sá renà
O nyá arae ma rele àwa ààbò
************************
Iyemanja oguntè kò alé o
Olorun boa lê o
Olorun mi to ko ale o
Olorun mi to ko ale o
************************
(KORIN EWE)
E mi faara oluaye
E mi faara oluaye
Ìyá olokun fará ojubonan
Ìyá olokun fará ojubonan, E mi faara oluaye
************************
Omi a guere, aguere wa o
Omi a guere, aguere e
Ìyá omi loyo mo l'ese
Omi a guere, aguere e
(Bate folha)
Ìyá omi loyo mo lese
Omi a guere, aguere e
************************
Kíní jé kíní jé odò
Yemonja ó.
Ki a sòrò pèléé
Ìyá odò mí ó
************************
(Bate folha)
Tá no mon se kwe
Iyemanja o o o, o ré re Iyemanja
************************
Ògùn óóó, Yemonja,
Ògùn ó,óó Yemonja
Ògùn óóó, Yemonja
É lódò e lódò sà wè a
Ògùn ó
Yemonja
Ìyá àwa sé wè,
Yemonja. Ó rere yemonja,
Ìyá àwa sé wè,
Yemonja dò ó rere yemonja
************************
Ìyá odò si omo gbè
Ki ènyin àwa orò
************************
(ILU)
L'ariwo oke, L'ariwo oke
L'ariwo oke Iyemanja
L'ariwo oke
L'ariwo oke iya sgba
************************
A Iya ni se
Ori odo, manja re
************************
É k'a máà ro ni ngbà
Òrìsà rè lodò.
É k'a máà ro ni rù ngbà
Òrìsà rè lodò
************************
Ìyálóòde, Ìyálóòde le´se ìbà ngbà,
Ìyálóòde, Ìyálóòde le´se ìbà ngbà,
************************
Maa ma jo gi Orisa Ibe
Orisa iya, Maa ma jogi Orisa Ibe, Orisa iya
Maa ma j ogi Orisa Ibe
Orisa iya, Maa ma jogi Orisa Ibe, Orisa iya
************************
Fàára mege, fàára ja. Fàára mege, fàára ja
Ìyá, Ìyá Fàára mege Fàára ja
************************
À oyó ìbà ngbà
Iyemonja pa le fun à
À oyó ìbà ngbà
Fé rè ni olúwà se
************************
A sagbè ìyá lé gbè
Òrìsà ìyá ìyá
A sagbè ìyá lé gbè
Òrìsà ìyá ìyá
************************
Yemonja sàgbà, Sàgbà mí rele.
Yemonja sàgbà, Sàgbà mí rele.
Sàgbà mí rele, Eru iya
Sàgbà mí rele
************************
Aka r'ibo
Aka osi iyamanja aja n'si
Aka r'ibo
Aka osi iyamanja aja n'si
************************
Ara wara, isu wara wa
isu l'ebe l'ebe
Ara wara, isu wara wa
isu l'ebe l'ebe
Ara wara, isu wara wa
isu ko ja de re
isu were, isu ko ja de re
isu ko ja de re
************************
Mí mò fere mì monja r’ewa
E mi ìyálóòde
E mí mò fere mì monja r’ewa
E mi ìyálóòde
************************
Iyemanja ogun te
Iyemanja mire re o
Aara ye
************************
Fara l’obe fara l’obe wàà
Oloye è
Fàára l’obe fara l’obe wàà
Oloye è
************************
Ala pada t'ogum a e
Ala pada t'ogum a e
************************
(HAMUNHA)
Olodo fi oluodo, Iyakekere
Olodo fi oluodo, Iyakekere
Olodo fi oluodo, Iyakekere
Olodo fi oluodo, Iyakekere
Ajala ajala, Iyakekere
Ajala ajala, Iyakekere
Ajala ajala, Iyakekere
Ajala ajala, Iyakekere
************************
A Oyo ague
Iyemanja mi rele
A Oyo ague
Iyemanja mi rele o
************************
(ALUJA)
È iya oro
Kini loja rè
Kini loja rè erú iya
Kini loja rè ó
************************
Yemonja odò,
Manja jé rè
Yemonja odò,
Manja jé rè
************************
Tójú l'yemonja e aráayé
Tójú l'yemonja e aráayé o
************************
Ta ni se in si
Ta ni bo ja re
Ta ni se in si
Ta ni bo ja re
************************
A odò nílé yemonja
A dò nílé àwa ààyò
************************
(ADAHUM)
Iya mandará
Iya mandará
Iya la pa ogum
Iya mandará
************************
Manja nile ko pa mege
manja nile ko pa me
************************
Assussa na d’oye
Assussa na d’oya
Assussa na d’oye
Assussa na d’oya
************************
Aguta’na d’oye
Aguta’na od’oya
Aguta’na d’oye
Aguta’na od’oya
************************
(Cantigas de Ogun)
S’ala re
Ògún onire ore gede
Ògún onire ore ko murajo
Ákòró onire ore gede o
************************
Ja re ja re ja ògún o
E ògún wa o ògún gbale
************************
Oní kòtò, oní kòtò n’ilé ògún
Ó ní àwa ajàjà, oní kòtò ó pa òbe.
************************
Iyaba ki mì jó ba jó ba murele
Kimi jó ba ó