ORIN TI OYA
Eèpàrìpàà! Odò ìyá!
(a mãe do rio niger-eèpàrìpàà.)
Eparrei oyá! Mesan orun
(salve a mãe dos nove espaços de orum)
Epahey Oyá! (Salve Oya)
(JINKA - BATA)
Ori n’la arabo
Ori n’la arabo, E l’oya
Ori n’la arabo
Ori n’la arabo, E l’oya
***********************
A ku le jo ko
A ku le jo ko, e l’oya
A ku le jo ko
A ku le jo ko, e l’oya
***********************
A ku le jo ko, iná
A ku le jo ko aarabo, e l’oya
A ku le jo ko, iná
A ku le jo ko aarabo, e l’oya
***********************
O ni ag’bo Iya e
O ni ag’bo Iya
Oya akaaro, O ni ag’bo Iya e
Oya akaaro, O ni ag’bo Iya
***********************
(DARO)
Ago be’riomon, le o, le o
Ago be’riomon, le o, le o
Te te orun ose mi o
Ayaba i so lo, lebe mi ro
O j’ala ara to run, wa o,
Kkin di oya mi ago
Oya mesan orun
************************
Iyaba mi sooro mi sooro do
Iyaba mi sooro mi sooro do ie
Iya lo fun fun kaara lo ta i o
O gà to kan, O ile be o o
O gà to kan, O ile be o o
Oya koia mi mesan orun lese Oya
Oya la fa oje, Oya la fa oje
Iyaba mi sooro mi sooro do ie
***********************
Ja ni pà nà, Ja ni pà nà
Ja ni pà nà, oya gbale
Ja ni pà nà, Ja ni pà nà
Ja ni pà nà, Oya onira
Ja ni pà nà, Ja ni pà nà
Ja ni pà nà, Oya bagan
Ja ni pà nà, Ja ni pà nà
Ja ni pà nà, Oya petu
************************
Koia koia ku si fo Oya è
Koia koia ku si fo Oya bagan
Koia koia ku si fo Oya è
Koia koia ku si fo Oya bagan
Iya ori, iya ori, iya oro
Iya ori, iya ori, iya oro
Iya ori, iya ori, iya oro
Iya ori, iya ori, iya oro
************************
A e to gàààà
Akara o de l’ogum gbale, mariwo
Akara je, mariwo,
A e to gà, Iya kooro ma forun gbe
kooro ma forun gbe, mariwo
************************
Sekete mi na l’oya
Oya olorun, mi na l’oya
************************
Mariwo mariwo
Oya ....... Ebo akufa
************************
Ke kiki ala kooro
Ke kiki ala kooro
Oro oro jeje
Oya oya, k'àrá ló jeje
Oya oya, k'àrá ló jeje
************************
Oya la oya
Ko be lo Oya
Mariwo
Oya dé e ó
Láárí ó
************************
Oya dé e ó
Láárí ó
Oya dé e láárí ó
Ó ní jé k'àrá ló
************************
(ILU)
Oya kooro nílé ó geere-geere
Oya kooro nlá ó gè àrá gè àrá
Obìnrin sápa kooro nílê
Geere-geere
Oya kíì mò rè lo
************************
Odò hó yà-yàyà
Yà odò hó yà-yà
************************
Tá ní a padà lóodò oya ó
Odò hó yà-yà
Tá ní a padà lóodò oya ó
Odò hó yà-yà
************************
A padà kò bé un òjòó, be l’oya
Kò bé un òjòó
A padà kò bé un òjòó, be l’oya
Kò bé un òjòó
************************
Òjè ní bo kíì oya ó,
Ojè ní bo kìí oya.
Ikú-fò wére-wére
************************
Oya ko kéé iró ko kéé ifá
To ri baba
Oya ko kéé iró ko kéé ifá
To ri baba
************************
Oya oya
Kòóro n’le ati motumbalé
Oya oya
************************
Mo se kwere ma fo run gbale Oya gan
Mo se kwere ma fo run gbale Oya gan
Oya mesan orun Oya de wo wo Oya gan
Oya de elemi alado
Oya de
Oya de elemi alado
Oya de o
************************
Oya tètè oya tètè oya gbálè,
Oya té-n-té ayaba.
Oya tètè,
Oya té-n-té oya
************************
Só só só ekuru
Oya gbálè ekuru
************************
Bíírí ibí bo won lojú
Ògbèri kò mòn mònriwó
************************
Ó gà i gà i lóko bíírí ibí
A sawo orò
************************
Oya lebe o
Be l’oya lebe lebe
************************
Oya se nun bó
Se nun bó leie leie
************************
E l’oya la pa mege
E l’oya la pa mege
************************
Oya n’ba oro oro
Oya la gba o
************************
Oya ko de o
Be l’oya be l’oya ó
************************
Oya dé be l’óya
Oya dé olorun
************************
E máa bo
E máa bo kì màà tí aláàgbaà e
Kì màà tí aláàgbaà e
Kì màà tí aláàgbaà
************************
Fí níigbó oya,
Fí níigbó oyá
Ó geere. Ó ní mónlè láárí ó
Fí níigbó oya
************************
Fí níigbó oya,
Fí níigbó oyá
Ó n’ka kwe re ni p apo ajimuda
Fí níigbó oya
************************
Té-n-té oya,
Té-n-té oyá
Ó n’ka kwe re ni p apo ajimuda
Té-n-té oya
************************
Oya kooro
Ó kooro ó
************************
Ó ní laba-lábá, ó lábá ó,
Ó laba-lába, ó lábá ó
************************
Olúa féé fé Sorí omon,
Olúa féé fé Sorí omon
************************
Ó na pa ki n’há
Gbálè
************************
Oya balè e láárí ó,
Oya balè.
Ádá máà dé f'àrá gè n gbélé.
Oya balè e láárí ó
************************
Ó i kíì balè e láárí ó,
Ó i kíì balè.
Balè balè kí nísé orò odò,
Ó kíì balè. E láárí ó,
************************
O iyaba nì lo kwe, ó fu lélé
O iyaba lóòkè odó
************************
Ó fu lélé a dé ó, ó fu lélé
Ó fu lélé a dé ó, ó fu lélé
Oya gbéle lóòkè odó
Ó fu lélé,
Oya gbamba lóòkè odó
Ó fu lélé,
************************
Gbàyìí l'à lèlè moro agan
Gbàyìí l'à lèlè moro agan
Iku bara àká
Layo layo, tenun tenun
Layo layo, tenun tenun
************************
Gbàyìí l'à l’eye
Gbàyìí l'à l’eye ó fu lélé
Gbàyìí l'à l’eye ó fun ajo
Gbàyìí l'à l’eye ó fu lélé
************************
Oya gbàle láárí ó, oya gable
Oya gbàle láárí ó, oya gable
Àdá máà dé f’ara gambele
Oya gbàle láárí ó, oya gable
************************
Gbàyìí l'à sé erù oya
Gbàyìí l'à sé erù iya ó
************************
Olorun megí kà forican gbélé
Oya bagan megí kà forican gbélé mo gbé olorun
Oya gbàlé forican gbélé
Mo gbé olorun
Oya gbàlé forican gbélé
************************
(ADAHUN)
Oya pada
Le pa
Oya pada
Le pa
************************
Iya ba l’odo
Le pa
Iya ba l’odo
Le pa
************************
Oya petu b’ewe sé b1ewe mà
Oya petu b’ewe sé b1ewe mà
************************
Oya mada b’ewe sé b1ewe mà
Oya mada b’ewe sé b1ewe mà
************************
Oya pada b’ewe sé b1ewe mà
Oya pada b’ewe sé b1ewe mà
************************
Oya mi zà zà no b’we
Oya mi zà zà no b’we ó
************************
Kòdá dé mo sé kòjáàde,
Kòdá dé mo sé kòjáàde
************************
E l’oya ko pa mejéé
Megéé in sare zà zà
E l’oya ko pa mejéé
Megéé in sare zà zà
************************
Té-n-té oya
Kini jé,
Té-n-té oya
Kini jé
************************
Ta ni àgó
Ta ni akofa l’ajo
Ta ni akofa l’ajo
Ta ni akofa l’ajo
************************
Olomi gue gue oya o
Olomi gue gue oya o
Olodu massa re o
Olomi gue gue oya
************************
E ero mi
E ero mà
Eru ma je massa r’ewa
************************
Pè ènyin ààbò,
Pè ènyin ààbò fàrá òjòó
Pè ènyin ààbò fàrá òjòó
Pè ènyin ààbò fàrá òjòó
************************
Oya be lebe mi ro,
Oya ba oro oro
Oya le be o,
Oya ba lebe lebe
Oya se run bo
Se run bo leye leye
Se run bo lo lerun leye
Se run bo lo lerun leye
Oya se run bo
Se run bo leye leye
************************
Oya ba o
Oya ba o
Oya lebe lebe
Oya lebe lebe
************************
Leye leye, Oya gambele
Leye leye, Oya gambele
Oya Iku lo jo, Oya Gambele
Oya Iku lo jo, Oya Gambele
************************
Oya akara le wa
Oya lo ko gbe la jo, Oya kara le wa
Oya akara le wa
Oya lo ko gbe la jo, Oya kara le wa
************************
Oya o
Oya o
Oya la ase, Oya
Oya o
N’ile koya le fun
Oya ko to n’ile sàngó
Fun n’ile gue
************************
(ALUJA)
Ku ri ade Ku ri a
Ku ri ade Ku ri a
************************
Àrá nì boye
Àrá nì boye ágó Oya
Oya gbále nì ákárá ó
Àrá nì boye ágó Oya gbále
************************
Oya o, Oya oriri
Oya o, Oya oriri
Da nì bosà run je vo
Da nì bosà run je vo
************************
A ba janga bo roro
A ba janga bo roro
************************
Jan be le
Jan be le, mu sa se
Jan be le
Jan be le, mu sa se
************************
(KORIN EWE)
È fi gan’ga
Fi gan’ga fìì gan’ga è
È fi gan’ga
Fi gan’ga fìì gan’ga è
************************
(IJESA)
È l’oya
Obà sirè
Oba saréoya
È l’oya
************************
A sarè lò nì
Oba oluwaye
Làárí o
************************
Fori gbàlé a ijo
Fori gbàlé a ijo
************************
(ILU)
Sé lé gbè
Sé lé gbè a n’lo
Sé lé gbè
************************