(JIKA)
Iba Orisha Iba Onile
*
Iba, iba, iba onile
Iba, iba, iba onile
Iba, iba, iba onile
Iba, iba, iba onile
***********************
(Korin ewe)
Sassanyin -
Èwẹ̀fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀ ooo,
Èwẹ̀fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀.
Bẹ̀ ni wọ́n ń bẹ̀, wọ́n ń bẹ̀ lókè,
Èwẹ̀fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀.
Wọ́n ń bẹ̀, wọ́n ń bẹ̀ ní ilẹ̀,
fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀.
Èwẹ̀fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀ ooo,
Èwẹ̀fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀.
Ìyá mi ló bẹ̀, Bàbá mi ló bẹ̀,
fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀,
Èwẹ̀fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀ ooo,
Èwẹ̀fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀.
Egúngún wa ló bẹ̀.
fẹ̀lẹ̀ bẹ̀ ní tó bẹ̀.
*
***********************
(AGABI)
Egunugun Kigbale
*
Ewo Nile
*
Òrò bí Òrò, Òrò bí Òrò.
Egúngún kọ́rọ̀ ilé,
Òrò bí Òrò, Òrò bí Òrò.
Ọya kọ́rọ̀ ilé,
Òrò bí Òrò, Òrò bí Òrò.
Ṣàngó kọ́rọ̀ ilé.
*
Onile Mo Bodo Ile
*
Nile Wa Alagbe
*
Agboula Ago Nile
*
O She Wara Wara
*
Saudações a Baba Olukutun, chefe de todos os antepassados / Loni Ojo Odun
*
Kiye Kiye Bo Iroko
*
Orisha Wa Iye
*
Ó fu lélé a dé ó, ó fu lélé
Ó fu lélé a dé ó, ó fu lélé
Oya gbéle lóòkè odó
Ó fu lélé,
Oya gbamba lóòkè odó
Ó fu lélé,
*
Omi Ro
*
Aluja
Egúngún
Egúngún ma je mi
Egúngún pa mi
Ebo ni mo ru
ki e mi agba mi je
**********************************
Egúngún bàbá mi o,
Ẹ wá wo mi o,
Ẹ wá bọ̀ mí lójú àìní,
Ẹ wá dá mi lóhùn.
**********************************
2. Òrò Àbí Òrò
Òrò bí Òrò, Òrò bí Òrò,
Òrò bí Òrò, Òrò bí Òrò.
Egúngún kọ́rọ̀ ilé,
Ọya kọ́rọ̀ ilé,
Ṣàngó kọ́rọ̀ ilé.
**********************************
Egúngún bàbá mi o,
Ẹ wá wo mi o,
Ẹ wá bọ̀ mí lójú àìní,
Ẹ wá dá mi lóhùn.
**********************************
K’òtún bájà dé o,
K’òtún ọba,
K’ó sìn nkon se,
Ẹégun ò pààràká…
Éégun a yè, a kíì gb’òrun,
Mo júbà r’ẹ Éégun mònrìwò…
Ìkú gbálé sálè…
Àse fún wa.
**********************************
Etutu tase, Kàdùrà wa gba o
Kalowo, kabimo n’ìlú Akesan o
Etutu tase, Kàdùrà wa gba o
Kalowo, kabimo n’ìlú Akesan o
**********************************
Omo loje, Omoloje, Omoloje o.
Omo loje, Omoloje, Omoloje o.
Egúngún mariwo