ORIN TI OSSAIYN
Ewé ó! (Salve as Folhas)
Ewé àsà! (Salve minhas folhas!)
(KORIN EWE)
Pèrègún aláwé titun ó,
Pèrègún aláwé totun.
Gbogbo pèrègún aláwé lésé,
Pèrègún aláwé titun ó
*********************
Fèlé bé àní tó bé ó, ewe
Fèlé bé àní tó bé.
Fèlé bé àní tó bé ó, ewe
Fèlé bé àní tó bé.
Àkò fèlé bé, Àkò fèlé bé
Àkà kò a kò fè lé bé
Fèlé bé àní tó béó.
*********************
Ja awùrèpépé
O pè ni o Pèlépèlé
Ja awùrèpépé
O pè ni o Pèlépèlé Sàngó
*********************
Móòfo èfó já e móòfo jé,
Móòfo já e ofa gogo
Móòfo èfó já e móòfo jé,
Móòfo já e ofa gogo
*********************
Ayra fu ge pwe igarata
Ayra fu ge pwe igarata
*********************
Fura no abado
Le lé ko le lé ko akun
*********************
Odundun baba teru lé
Odundun baba teru lé
Baba teru lé male teru lé
Odundun baba teru lé
*********************
Ti nu wa le no kre l’ewa
Ti nu wa le no kre l’ewa
Ti nu wa le no kre l’ewa
Ti nu wa le no kre l’ewa
Ofe ri, ofe ri, ibi aka
Kan g’ere le g’ere le ke odo
Osibata lu odo ke omi
Ti nu wa le no kre l’ewa
*********************
Efun gbale e ko’juman o
Efun gbale e ko’juman
kunkunndunkun ori lewe
Efun gbale e ko’juman
*********************
I rin-rin ewe tori ó
I rin-rin ewe atori
A nse bale a isaba bain baro
A isaba yaba sorun, Mojé f'orí okon
I rin-rin látòní bàbá ketun
I rin-rin látòní bàbá ketun
I rin-rin látòní bàbá ketun
*********************
Ogun tana tana de
Tana de tana de o
Ogun tana tana de
Tana de tana de o
*********************
Ofa e mi ofa gbogbo
Ofa e mi ofa gbogbo
Ofa e mi ofa gbogbo le se
Ofa e mi ofa gbogbo
*********************
Aba ju la ju le we
Aba ju la ju le wa
Aba ju la ju le we
Aba ju la ju la osogun
*********************
Kí ka kí ka oya gbálè ó,
Kí ka kí ka oya gbálè.
Oya bi kosso ewé mi kò sílè
Kí ka kí ka oya gbálè.
*********************
Kí ka kí ka oya zan buruku o
Kí ka kí ka oya zan buruku
Zan buruku o baba te ru le
Kí ka kí ka oya zan buruku
*********************
E a gbéèdè
A gbéèdè
Ewé a gbéèdè nbo,
E a gbéèdè
*********************
Ò mò jéwé mo sòrò ò, ó
Mò jéwé pé mo sòrò.
Ò gbè lówó mi ò gbè lówó mi ò
Mò jéwé pé mo sòrò
*********************
Ipesan ewe lará
Ta ni wá l’axé ke su
Ipesan ewe lará
Ta ni wá l’axé ke su
*********************
Dan dara mada o
Ewe dan dara mada
Esu Onan firi a Dan
Ewe dan dara mada wo
*********************
Àbámodá àbá mi kò se àìse
Àbá alágemo bá dá,
L’òrìsà Okè ngbà
Mo dá àbá owo
*********************
Ewé ófé gbogbo akoko
Ewé ofé gbogbo akoko
Awá li li awá oro
Ewé ofé gbogbo akoko
*********************
Ode Ìyá ofa Ìyá
Piria, Piria Piria
*********************
E ofere,
Ofere me ri o, e ofere
*********************
Iroko a popo ojo
Awe gue bade se mi
Alado igi igi a popo ojo
Aara mi bo ode de bà
Ode de bàn
Aara mi bo ode de bà
Ode de bàn
Aara mi bo ode de bà
*********************
Eró iroko ki zo eró
Iroko ki zo e
Eró iroko ki zo eró
Iroko ki zo e
*********************
Òjòó máà òfuurufú,
Òjòó máà òfuurufú.
Òjòó máà àrá inón
Òjòó máà òfuurufú.
*********************
Ti éwerépepe
Omi pére pe
Éwerépepe
Okò ni pere pe
*********************
Àwa dàgò l'ojú ewé,
Àwa dàgò l'ojú e mò oògún.
A dàgò l'ojú ewé l'ojú ewé,
A dàgò l'ojú e mò oògùn
*********************
Ó igi igi òtá àrònì ó,
Ó igi igi òtá àrònì.
Ewé bo igi igi ní àwòrò oògùn mòn,
Ó igi igi òtá àrònì
*********************
Ewé oògùn mòn,
Ewè àsà, Ewé oògùn mòn l'ònòn
*********************
Òpó lè àsà subú
Nigbó rú igi igi àkàbà.
Òpó lè àsà subú bàbá
Nigbó rú igi igi àkàbà
*********************
Ewé àkàbà bo ènyin,
Ewè àkàbà bo ènyin.
Pèrègún ewé àkàbà
Bo ènyin ewé ewé
*********************
Ìyá omi ìmonlè ni ewé awo ìyá omi ìonlè. Asèki obè ewé,
Ìyá omi imonlè ni ewé awo. Ìyá omi ìmonlè àsèki obè ewé, ojú odò ayé
*********************
Pèrègún látòní ó,
Pèrègún látòní ó.
Àkábá àwa elegé
*********************
Ojujumã é Dágunróo,
Ogungun a logê
Ojujumã é Dágunróo,
Ogungun a logê ó
*********************
Assa ewe caxancho
Assa ewe caxancho
Ewe comojé ewe comassá
Assa ewe caxancho
*********************
Kúkúndùnkú baba tete nun
Kúkúndùnkú baba tete nun
Male tete nun, male tete nun
Kúkúndùnkú baba tete nun
*********************
Oni Tafa’ra ode, ere mi ná
ke mi kemi ojuoro, ere mi ná
Tafa ojo
Ere mi ná
*********************
Ofere, ofa e mi eja
Ofere, ofa e mi eja
Te te omi, Ojuoro, Osibata
Ofere, ofa e mi eja
*********************
Sa we le baba tete nun
Sa we le baba tete nun
Baba tete nun, male tete nun
Sa we le baba tete nun
*********************
Ewa makaxá golonã
Ewa makaxá golonã
Peregun kibican
Ewe makaxá golonã
*********************
Ewa makaxá golexin
Ewa makaxá golexin
Afomã kibican
Ewa makaxá golexim
*********************
Ewé e ní àsà ki ó jé,
Ewé jé si gbogbo òrìsà.
Ewé ki mò àsà ki ó jé bàbá,
Ewé jé si gbogbo òrìsà
*********************
Ewe obo iroko
Ewe obo sabi ejé
Ewe obo iroko baba
Ewe obo sabi ejé
*********************
Ará àwa ìrokò isó
Ará àwa ìrokò isó
*********************
Awede ó ti móòkè kún awede, ó ti móòkè kún
Awede ó ti móòkè kún awede, ó ti móòkè kún
Awede ó ti móòkè kún awede, ó ti móòkè kún
Awede ó ti móòkè kún awede, ó ti móòkè kún
*********************
Eru jéé-jèè erù jéé-jèè
Tàwa ni mòsà. Ni bàbá jé ó, erù
Jéé-jèè e ní ewé ó
*********************
Beere ewe o gege
Beere ewe o gege, i dan ko ba ewa
Iba ri baba iba o, iba re ewe iba Danboro,
Na re wa ase dara e
*********************
Opolo Òsónyìn isi ku
Koku ru i ti a kaka
Opolo Òsónyìn isi ku baba
Koku ru iti a kaka
*********************
Ilu aje iki Iroko
Ki l’ose mo beere
Ilu aje iki Iroko baba
Ki l’ose mo beere
*********************
Sere sere awa mi ma sere
Sere sere awa mi ma sere
Ba e ro ko, kolobo yo sere
Ba e ro ko, kolobo yo sere
Iya mi omon male kan sere
Iya mi omon male kan sere
Ba iya dudu ma le kan sere
Ba iya dudu ma le kan sere
*********************
Ewe gyn awa te gyn
Ewe gyn awa te gyn
Omo Olufan, Aganju aye
Ewe gyn awa te gyn
*********************
Oni se be wa, Oni se be wa
Baba ebo Oni se be wa
Oni se be wa, Oni se be wa
Baba ebo Oni se be wa
*********************
Ewe ni asa fo je
Ewe ni é orixa
Ewe ni asa fo je baba
Ewe ni é orixa
*********************
Ewe gbogbo aki se gun
Ewe gbogbo aki se gun
Ewe bi kan baba asa fo je
Ewe gbogbo aki se gun
*********************
A ibo
Koya koya koya, a Ibo
A ibo
Koya koya koya, a Ibo
*********************
Ewe Ofere, ofere je je o
Ewe ofere jeje o
Ewe Ofere, ofere je je o
Ewe ofere jeje o
*********************
Oni ta fa ode, ere mina
Kemi kemi ojuoro, ere mi na
Ta fa r’ojo, ere mina
*********************
Ofere ofa emi eja
Ofere ofa emi eja
Tete r’omi ojuoro osibata
Abado ojuoro, elua o
Ofere ofa emi eja
*********************
Ba in semi semi
Lo in loin loin
Igi were ata Iroko
Igi were ata ironi
*********************
(ILU)
Boro godo, boro godo
Boro godo osi de wa
Bara gada ossaiyn ile
Boro godo, boro godo baba
*********************
Àta rú nbo mo júbà ru,
Àta rú nbo mo júbà ru,
Àti loko mo juba ru loya
Àta rú nbo mo júbà ru,
*********************
Òsónyìn aláwo wa,
Sàwúre pípé òrisà ewé
*********************
Agè maré agè maré ó
Párá ki so dan, Agè maré
*********************
Kíti-kìti igbó alé ní won ó
Párá ki so dan.
Kíti-kìti igbó alé ní won ó
Párá ki so dan.
*********************
(HAMUNHA)
Òsónyìn aláwo òrò,
Agè meré ewé sigbó dáfá
*********************
Ìgbàgbó sé mi agè ni òró
Ae ae
Ìgbàgbó sé mi agè ni òró
Ae agè
*********************
Ìtòróró agè agè tòróró, òsónyìn
Ìtòróró agè agè tòróró, òsónyìn
*********************
(Bêbado)
Perewe perewe
A rum t’se tô
Perewe perewe
A rum t‘se tô
*********************
(ADAHUM)
A iji ko p’ele, a ipe o
A iji ko p’ele, a ipe o, a ipe male
Ìtòróró , igi, igi Ìtòróró, e bagam
Ìtòróró , igi, igi Ìtòróró
*********************
A iji ko p’ele, iko pe le, a ipe male
A iji ko p’ele, iko pe le, a ipe male
Ìtòróró ipe ma le, Ìtòróró, ipe mo le
Ìtòróró ipe ma le, Ìtòróró
*********************
Awa ó, ki Odé dere
Awa ó, ki Odé dere
*********************
Awa ó, ko de tan nha nha
Awa ó, ko de tan nha nha
*********************
Ìtòróró já di ó
Ìtòróró já di ó
*********************
(ALUJA)
Afuma bikan, sen sen,
Afuma bikan, sen sen
*********************
Fa'ra mi zan zan no gbwe
Fa'ra mi zan zan no gbwe lo
*********************
A Igbo, a Igbo lonon
A Igbo, a Igbo lonon
*********************
A idu a, Otin a idu
A idu a, Otin a idu
*********************
Mariwo, ki lo fo ni se
Mariwo ki lo fo ni se, o
*********************
(IJESA)
O, o, o, o, o, o, o,
Òsónyin ìrúnmonlè. Ìrúnmonlè kì a dé o, o
*********************
(Sòssóyìn Vitor de Iyemanjá)
Agè máà inón ó pa àdá.
Agè máà inón ó pa àdá ó
*********************
(Sòssóyìn Anilson Òssóiyn)
Ewé, ewé, ewé
Agè, isó tó adáfá
*********************
Àwúre kùtú òsónyìn,
Àwúre kùtù ní ewé ó
*********************
Agè figbó e ti móòkè kún,
agè figbó e ti móòkè kún
*********************
Agè mi moia di mokusa
Agè mi moia di mokusa
Agè mi moia di mokusa
Agè mi moia di mokusa
*********************
Ago nile ague o
Ago nile ire
Ago nile ague o
Ago nile ire
*********************
Òsónyin ilé aráalé ó,
Òsónyin ilé. Aráalé ó,
Òsónyin e ti móòkè kún.
E ti móòkè kún, Òsónyin ire
*********************
(Cantiga para ir embora)
Ferere do ni sa n'lo
Ferere do ni sa n'lo