ORIN TI ÈSÚ
Laróyé Èsú, Mo Jubà
(Meus respeitos ao Mensageiro)
(ILU)
A jí kí barabo e mo júbà,
Àwa kò sé
A jí kí barabo é mo júbà,
E omodé ko èkò èkó
Ki barabo e mo júbà
Elégbára èsú l’óònòn.
*********************
Bará ó bebe tirirí l’ònòn
Èsú tirirí,
Bará o bebe tirirí l’ònòn
Èsú tirirí.
*********************
Elégbára, elégbára
Elégbára àgò nbo nbo
********************
Góké góké odára,
Odára bàbá ebo
Góké góké odára,
Odára bàbá ebo
********************
Góké góké nidánón,
Odára bàbá ebo
Góké góké nidánón,
Odára bàbá ebo
****************
Inón inón mo júbà e e mo júbà
Inón inón mo júbà e àgò mo júbà
****************
Barálojiki èsú logbe wa
Ara e e
Barálojiki èsú logbe wa
Ara e e
****************
Só só òbe, Só só òbe
Odára kò l’orí erù ejo, laróyé
Só só òbe, Só só òbe
Odára kò l’orí erù ejo, laróyé
Só só òbe,
Odára kò l’orí ebo.
****************
Èsù so soròkè,
Elégbára kí a awo
Èsù so soròkè,
Elégbára légbáa ó.
****************
Àgò nbo nbo, laróyé
Àgò nbo nbo, laróyé
Àgò nbo nbo, laróyé
Àgò nbo nbo, laróyé
****************
Èsù o
Èsù o èsù l’ònòn
E f’orun gbale iso
****************
Oni sakpata ago n’ile
Ago n’ile, mo fo ri gbale
Oni sakpata ago n’ile
Ago n’ile, mo fo ri gbale
****************
Èsù o
Èsù o lonan, mo fo ri gbale
Èsù o
Èsù o lonan, mo fo ri gbale
****************
Soròkè Odara
Odara baba ebo
Soròkè Odara
Odara baba ebo
****************
A ketu
E danda Èsú
Alaketu
E danda Èsú
****************
Odi legba o, Kinijan
Legba o, Kinijan
Èsú legba o, kinijan
Odi legba o, Kinijan
****************
Èsú legba, sekete
Èsú legba, sekete
Èsú legba, sekete
Èsú legba, sekete
****************
(AGUERE)
Èsú wa jú wo mòn mòn
Ki wo odára. Laróyé
Èsú wa jú wo mòn mòn
Ki wo odára
Èsú awo.
****************
Odára ló sòro,
Odára ló sòro l’ònòn
Odára ló sòro e ló sòro
Odára ló sòro l’ònòn.
****************
Odára sa we pe, èsú
Odára sa we pe l’ònòn
Odára sa we pe, èsú
Odára sa we pe l’ònòn
****************
Elégbára sekete
Elégbára sekete l’ònòn
Elégbára sekete
Elégbára sekete l’ònòn
****************
Elégbára èsú laalu
Elégbára èsú laalu légbára
****************
Òjísé pa lê fún awo,
Odára pa lê soba
Òjísé pa lê fún awo,
Odára pa lê soba.
****************
Elégbára léwá légbára
Èsú a jú wo mòn mòn ki a awo
****************
Kò mo nrí ìjà rè ó ìjà rè ó èsú olóònòn.
Kò mo nrí ìjà rè ó ìjà rè ó èsú olóònòn.
****************
Ó jí gbálè á kàrà ó, ´
Èsú soròkè
Ó jí gbálè á kàrà ó,
Èsú soròkè
****************
(EGO)
E má won léébá nón,
Kò rí ìjà
E má won léébá nón,
Kò rí ìjà
E má jékì, kò rí ijà
E má jékì, kò rí ijà
****************
Olóònòn àwa bará kétu
Olóònòn àwa bará kétu
****************
Èsù so sóròkè.
Elégbára ki a awo.
Èsù so sóròkè.
Elégbára légbáaó
****************
Kétu ké
Kétu e
Èsú alákétu
Kétu ké
Kétu e
Elégbára kétu
****************
(BATA)
A pàdé olóònòn e Mo júbà òjísè
Àwa sé awo,
Àwa sé awo,
Àwa sé awo, Mo júbà òjisè.
****************
Elégbára réwà, a sé awo
Elégbára réwà, a sé awo
Bará olóònòn àwa fún àgò
Bará olóònòn àwa fún àgò
****************
A jíki ire ni èsú,
Èsú ka bí ka bí.
A jíki ire ni èsú,
Èsú ka bí ka bí.
****************
Elégbára èsú
Ó sá kéré kéré
Èkesan bará èsú
Ó sá kéré kéré.
****************
E elégbára
Elégbára èsú aláyé
E elégbára
Elégbára èsú aláyé
****************
Ó wá lésè l’abowolé s’orí àgbékó ìlèkùn,
Ó wá lésè l’abowolé s’orí àgbékó ìlèkùn.
****************
Ale Èsù,
Èsù ko bo ko
Alé Èsù,
Èsù ko bo ko
****************
(IJESA)
Èsù onà èsù onà
Mo si re lode elégbára
Légbára n ire
Èsù onà ke wa o
****************
Èsù ta wa n’ila re
Èsù ta wa n’ila re o
****************
Iji ka èsù ara ka nbo
Iji ka èsù ara ka nbo
****************
Boroko boroko boroko
Sekete elégbára
Sekete èsù légbára
Sekete e lé wa
****************
(SAMBA)
Beregue um já um jaja
Beregue
Beregue um já um jaja
****************
(HUNTO)
O isa, odara, bergue be do ma isa
O isa, odara, bergue be do ma isa
****************
(HAMUNHA)
Elégbá mayo ku dun
Èsù kere kere
****************
Baraketu, baraketu Èsù Tiriri
Baraketu, baraketu Odaraó
****************
Indo kwe Otin Orisa
Indo kwe, Otin Orisa
****************
Èsù a inón kò
Yemonja kó nta ródò,
****************
Àgòlóònòn àwa pè nbo, àgòlóònòn e
****************
Alákétu rè
Kétu bará èsú máa ló.
****************
Bára je n’tan á nlo,
Bára je n’tan máa ló ilé.
****************
ORIN TI IPADÉ EXU
(ILU)
E ina mojubà
Ina ina mojubá aiyé
Ina mojubà
Ina ina mojubà.
****************
E ina korokà
Ina ina korokà aiye
Ina korokà
Ina ina korokà aiye.
****************
E ina ko wà ba
Ina ina ko wà ba aiye
Ina ko wà ba
Ina ina ko wà ba aiye.
****************
Ojisè pale fun wáo
Odara pale sobà
Ojisè pale fun wáo
Odara pale sobà.
****************
Alé massa
Baissà baissà
Alé massa
E baissà baissà
****************
E olopà ogun
Baissà
Olopà ogun olopà ogun
Baissà.
****************
E egigun roko
Baissà
Egigun roko egigun roko
Baissà.
****************
E wale baba o, oni baba ija
Wale o onijà
Wale baba o ae
Wale o onija.
****************
E oni esà arole
Ina mi simi ba oni e
Baba esa këran
Olomo mi simi ba bo dele.
****************
Ojisé pá le fun ao
Odara pá le sobá
Ojisé pa le fun á
Odara pá le sobá
Otin ni sakómó
Saio be oni saio bé
****************
Otí ni sà komo
Saiyo bèè bèè
Oni saiyo bèè.
****************
(KORIN EWE)
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Esù agbó oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Ogun akooro oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Ode arole oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Iyemanja oyo oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Oya Oriri oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Omolu arawe oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Osun ewunji oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Bàbá Oloroke oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Obatala oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Egun eni soloro
Esan foloro atoro sé
Oduduwa oloro
Esan foloro atoro sé.
****************
Apaki yeye sorongà
Apaki yeye sorongà
Iyà mo ki ò mama pani
Iyà mo ki mama sóró
Bà abà de waju wani, boni
****************
Iyà mi là gba wà o
Iyà mi soro là gba wà o yeye.
****************
Apaoka já omo
Oyado igui-igui ayaba
****************
(IJESA)
Yèyé yèyé oke ó
Yèyé yèyé oke ó
Ayra la fo npa ó
Òlóo mo ke wa po
Afofo la po nise
Ori omo ke wa po
*****************
(ILU)
Iyàmoró dodó, Iyàmoró
Ibisi lo biwà
****************
Ajimuda ko ré lé iya
Abà ijena,
Ajimuda ko ré lé iya
Abà ijena,
****************
Ogan lejó
É ogan lejó sare wa
Ogan lejó.
É ogan lejó sare wa
****************