ORIN TI SÀNGÓ
Ká wòóo, ká biyè sí!
Podemos olhar vossa real majestade!
(porque era considerado honra poder olhar o oba erguendo a cabeça diante dele)
(ILU)
Oba ní sà rè lóòkè odó
Ó bé rí omon
Oba ní sà rè lóòkè odó
Oba kòso ayò
************************
Máà inón inón
Máà inón wa inón inón
Oba aganju
Máà inón inón
Máà inón wa inón inón
Oba agodo
Máà inón inón
Máà inón wa inón inón
Oba Baru
Máà inón inón
Máà inón wa inón inón
Oba intile
Máà inón inón
Máà inón wa inón inón
Oba mode
************************
Oba kòso aráaye
Máà inón inón
Oba kòso aráaye
Máà inón inón
************************
Aláà kòso e mo júbà
Á ló si oba ènyin
Oba tan jé ló síbè
Ló si oba ènyin
************************
A sìn e doba àra
Àra yìí ló síbè ènyin
A sìn e doba àra
Àra yìí ló síbè ènyin
************************
Sàngó te re mi na iinjo de
Te re mi na iinjo de
Te re mi na iinjo de
Sàngó te re mi na iinjo de
************************
(falado)
Ara ni lo kilose ki mi lo ri,
Agongon ala fum alareo,
Ojinse orun aye,
Ojinse orun aye, Kìni bà, Kíní bà,
Oba seere a Loko
Aganju kinwajo onile o
Aládó kíní ìba,
Kíní bà àrá won sè.
Kíní bà,
Ajangu isolá àwúre
************************
A ijo loko
Oyo n’le
Ki loxe io
Kiniba oba n’se
************************
I ki i ki tere o luodo
Oba la do
Oba ko ke mayo lerio
Oba lu ayweo
************************
Wunhe wunhe
Oba de ko oba ni tawege
Wunhe wunhe
Oba de ko oba ni tawege
************************
Were were were
Ode massa
Oba ba mi ose
Oberiomà
************************
Omoroba mosire, omoroba fe insi
Ata murere, murereo, omoroba mosire
************************
Kin kin moyo, omoroba kocile
Kin kin moyo, omoroba fé insi
Omoroba kocile, omoroba fé insi
Omoroba kocile, omoroba fé insi
************************
Oba kin kin mayo sere
Alado mi moroba Ko jure
Kin kin moyo e e e
Omoroba ko sule
************************
E Obalase Sango
Oba in oba l’ase oba
Obalase:
Agodô / Afonja / Aganju / Axabo / Baru / Intile / Igbona / Mode / Mofe / Kosso / Olufan / Erungan / Jakuta / Sogbo / Bade
(Oba in oba l’ase oba)
Oba tô tô aro
Oba in oba l’ase oba
Oba in oba l’ase oba
Oba in oba l’ase oba
************************
Mabo sin sin mabo ye ye
Mabo sin sin oya ilu
Oba la sango ilu igbi
Ayra o oba do de
Ayra o Ayra
Ayra o Ayra
Sango do de la ogue
Ayra o oba do de
************************
(ADAHUN)
Ogum ala rá o
Mó de in ma de odo
Ayra irunmole Obanise
Kìni na irá
************************
Made ola oman da more
Made owo oman da more
Bi oman da lade
wara o da lewi
Bi oman da lade
Bi ti pa oro ni o … ako vi tare
wara wara bi more
wara wara bi more ako vi tare
wara wara bi more ako vi tare
************************
Ayra pá de
Ayra pá de
Ayra, Ayra
Ayra pá de
************************
Loko me fara pabo
Loko me fara pabo
Ayra mó Je
Loko me fara pabo
************************
Ayra ó, ore gédé pa,
Ore gédé
Ayra ó, adjaosi pa...
Adjaosi
Ayra ó, ebora pa...
Ebora
************************
(ALUJA)
(Falado)
O dide o, Aare mu Ko dide
O dide o, Aare mu Ko dide
Jo bi o bire Bàbá era kwe
Bàbá kolofin Sango boro
Are mu komo dja
egun koba lo mi o
Be un si, be un si
Un ko ba lo mi o
Be un si, be un si
Un ko ba lo mi o
(Falado)
O dide o, Aare mu Ko dide
O dide o, Aare mu Ko dide
Jo bi o bire babá era kwe
Baba ko lofin Sango boro
Are mu komo dja
egun koba lo mi o
Beba mi, bê aman
Baba oxe ki mi fo bate
Beba mi, bê aman
Baba oxe ki mi fo bate
(Falado)
Iyamasse ló fi Sàngó
Iyamasse ló fi Sàngó
Ìyá erungan Oyo Oba bitiko
Òrixá ejá Igbo
Ejá oro din din din, Ejá oro
Ejá oro din din din, Ejá oro
************************
Sô Alado
kini ba onije osile, sô alado
************************
Kíní bà oya dee
Kíní po po oma deyo
************************
(Falado)
Wara wara, Orinje n’le àrá oju
Wara wara, Orinje n’le àrá oju
Lò bí orinje Oba
Oke oba to to aro
To e tó ri oba la jo
Sàngó e tó ri oba
************************
Sire wa, sa fi ra
Ada Kooro mi Dada
Sire wa, sa fi ra
Ada Kooro mi Dada
************************
Awa n’la in Oba Kosso
Ki l’osekii l’ose
Awa oyo oba n’ile
Awa oyo oba n’ile
************************
Ki no sa fo já Oba lá jo
Ki no sa fo já Oba lá jo
Ki no sa fo já Oba lá jo
Ki no sa fo já Oba lá jo
************************
Onílá lòkè, baàyònnì
Gbáà yìí l’àsé onílá lòkè, baàyònnì
Gbáà yìí l’àse
Gbáà yìí l’àsé onílá lòkè, baàyònnì
Gbáà yìí l’àse
************************
Sàngó e pa bi àrá aáyé aáyé
Sàngó e pa bi àrá aáyé aáyé
************************
kawoooo, kabiecile
kawoooo, kabiecile
Kawo e kole
Orixa i Mogbá
e loci, e loci
e loci kebiecileeeee
kawoooo, kabiecile
kawoooo, kabiecile
************************
Fírí ínón fírí ínón
Fírí ínón bàiyìnjó
Máà ínón, máà ínón
Fírí ínón bàiyìnjó
************************
Àjàká máa bè ká wòóo
Àjàká máa bè ká wòóo
A e bàbá
Àjàká máa bè ká wòóo
************************
Bàrà ó kíì bàrà ó kíì bàrà,
elébàrà ní ó
************************
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
************************
Tójú l'yemonja e aráayé
Tójú l'yemonja e aráayé o
************************
Oba xere alado pabo
Oba xere alado pabo
Xango ba da iroko bemio
************************
Olo mina dada e
Olo mina dada e o
************************
E kole mo d’àgó
E kole mo d’àgó e
************************
Oba sà rewà
Ele mi jéé jéé
Kù tù kù tù awo dé rè sé
Oba sà rewà
************************
Ba ilase nu ya
Ba ilase nu ya
Ogodo masse ero
Ogodo masse oya
************************
Gbáà yìí l'àsé nu ya
Gbáà yìí l'àsé nu ya
Ogodo masse ero
Ogodo ma de oya
************************
Iná ba otí, ba otin
Iná ba otí , bo awo
************************
Aganju ke mado orixá ogodo ke mada xango
E e e aganju ke mado orixa
************************
Ya massemale koro in bada iko
Ya massemale koro in bada iko
************************
Ka ka ia ia mambaia,
Ka ka ia ia mambaia, ia io ia io
Ka ka ia ia mambaia,
Ka ka ia ia mambaia, Orogbo ni Sango
************************
(TONIBODE)
E me moin
Samba la o
E me moin
Samba la o
************************
E me moin
Oba lawo
E me moin
Oba lawo
************************
(BATA)
Àjàká òké òrìsá
Àjàká òké òrìsá
************************
Ò be ri ó, ní dàda sókun,
Àwa ri ó ó ní dada sókun.
************************
Aé aé ó gbè lê mònsó ojú omon
Aé aé ó gbè lê mònsó ojú omon
Oba olórí légé ó ni yé oba olórí
Ilú àfonjá dé ó, aé aé bé, ri ó
Aé aé bé, ri ó aé aé bé, ri ó
Ò bé, ri ó ( ikú kójáàdé-ó kótà èrú)
************************
Agonjú órìsá awo ògbóni
Agonjú órìsá awo ògbóni
Àwúre, sàngò àwúre
Ògbóni, ògbóni, ògbóni
Àwúre, sàngò àwúre
************************
Káwòóo, káwòóo
Sàngò dàhòmì
Káwòóo ka biyè si e
Sàngò dàhòmì
************************
Oba sérée òwa fé yìí sìn
Oba sérée òwa fé yìí sìn
Oba àwa òjòó oro ní oba
Oba sérée òwa fé yìí sìn
************************
Eléèmíi ó gígún, àrá funfun. Eléèmíi ó gígún, àrá funfun
************************
(KORIN EWE)
Àwúre lê, àwúre lé
Àwúre lê, àwúre lé
Ada ko dina, Fu ro ro Gbale
Àwúre lê, àwúre lé kólé
************************
Àwúre lê, àwúre lé kólé
Àwúre lê, àwúre lé kólé
Àwa bo nyin maá ri àwa jalè
Àwúre lê, àwúre lé kólé
************************
Ó fì làbà, làbà.... Ò fì làbà
Ó fì làbà, làbà.... Ò fì làbà
************************
N’le baba wa la le ja o
N’le baba wa le ja o
************************
Ó jìgòn àwa lé npé ó jìgòn nlá
Ó jìgòn àwa lé npé ó jìgòn nlá
************************
E kí yemonjá ago, tapa tapa
E kí yemonjá ago, tapa tapa
************************
(ALUJA)
Ala baawo ahun kwere
Oba n'le
*********************
(IJESA)
E maaman sooro, Oba. E maaman sooro
E di maaman ju'oro imole
Godo godo ara e
A ré re
************************
Godo godo ara in sooro
Ije mi oro
A oba in sooro
Inje in sooro
************************
Oba eeee godo
Oba imole
************************
Oba lá irumole, oba lá, irumole
Oba lá irumole, oba lá, irumole ó
************************
ORIN RODA TI SÀNGÓ
Iyá olú aré iyó
Iyá olú aré iyó
Ibeji mado pé
Iyá olu are
Pè ti lé omon pè ti fò
Alaré iyá orobá
Wá dodê adupé ô
************************
Àwa dúpé ó oba dodé,
Àwa dúpé ó oba dodé.
Sóngó àfònjá oba dodé,
Àwa dúpé ó oba dodé
************************
A dúpé ni mòn oba e kú alé
A dúpé ni mòn oba e kú alé
Ó wá, wà nilè,
A dúpé ni mòn oba e kú alé
************************
A dúpé ni ri re obara si
A dúpé ni ri re obara si
Ó wá, wà nilè,
A dúpé ni ri re obara si
************************
Fé lè fé lè
Yemonja wé okun
Yemonja wé okun
Àgó firè mòn
Àgó firè mòn
Ajaká igba ru , igba ru
Ó wá e
************************
Sàngbá sàngbá
Didé ó níìgbòdo,
Ode ni mó.
Syìí ó, òní ó
************************
Tan ba e de ari bo
Ero syiio, Tan ba e de ari bo
Òní dàda , àgò lá rí
Òní dàda , àgò lá rí
************************
Dàda má sokun mò
Dàda má sokun mò
Ò feere ó ní feere
Ó bgé l`orun
Bàbá kíní lonòn da rí
************************
Báyànni gìdigìdi , báyànni olà
Báyànni gìdigìdi , báyànni olà
Báyànni adé , báyànni òwò
Báyànni adé , báyànni òwò
************************
Fura ti ´ná, fura ti ´ná e,
Fura ti ´ná, àrá lò si sá jó
Fura ti ´ná, fura ti ´ná e,
Fura ti ´ná, àrá lò si sá jó
************************
Ìbà òrìsà, ìbà onílè
Onílè mo júbà o
Ìbà òrìsà, ìbà onílè
Onílè mo júbà o
************************
Káwòóo, káwòóo
Sòngó dàhòmi.
Káwòóo ká biyè sí e
Sòngó dàhòmi
************************
Pa po o
Pa po tanga la
Tanga la o toro e le
Papo o eru jeje
************************
Irá abê
Irá arô
Irá arofo
Lodosun mãiran agoman
Lodupé obá,
Lodidi obá
Ló déin
Iyá massemalê
Ojô olé ibê
Obá lé loko ofô
Obá lé loko ofô
************************
(ILU)
Òràn in a lóòde o
Bara enì já, ènia rò ko
Oba nù ko´so nù rè lé o
Bara enì já, ènia rò ko
Oní máa, ni wó èjé
Ó níìka wòn bò lórun kéréjé
ó níìka wòn bò lórun kéréjé Àgùtòn
Ìtenú pàdé wá lóna Í níìka si relé
Ibo si òràn in a lóòde o
Bara enì já, ènia rò ko
Oba nù ko´so nù rè lé o
Bara enì já, ènia rò ko
Oní máa, ni wó èjé
************************
Oba sérée la fèhinti
Oba sérée la fèhinti
Oba ni wá ìyé bè l´órun
Oba sérée la fèhinti
************************
Eye kékéré adó òsi iya re re
Ìyá l´odó mase
Eye ko kéré soko ìyágba
L´odò mase
************************
A níwà wúre
A wúre níwà
A níwà wúre
A wúre níwà
Oba lùgbé obaladó
Obaladó rí sò
Obaladó
************************
Olówó
Kó mà bò , mà bò
Kó mà bò
Olówó
Kó mà bò , mà bò
Aláààfín òrìsà
************************
Omo àsìkó bèrè
Èkó inón, èkó inón
Omo àsìkó bèrè
Èkó inón, lóòde roko
Omo àsìkó bèrè
Èkó inón, èkó inón
Omo àsìkó bèrè
Èkó inón, èrù njéjé
************************
Obara lojo ko kéré kè
Igbona kéré kè
Obara lojo ko kéré kè
Baru kéré kè
Aganju lojo ko kéré kè
Agodo lojo ko kéré kè...
************************
E ain jele kobele
A iná eru jéé jéé
************************
Bani koloja um be loko
Obi onije
Bani muse um beloko
Bani koloja um beloko
Bani mu se oba de
************************
Pamole morilé
Obo mònriwò
Gu do gu do pè
************************
(Cantigas para chamar orixa)
Olúwáiyé
Koya koya
************************
Onílá lòkè Baàyònnì
Gbáà yìí l’àsè
Onílá lòkè Baàyònnì
Gbáà yìí l’àsè
************************
Kòò lè Kòò lè ni sàrè Ògun ó
Iyemonja
Mogba Kòò lè ni sàrè Ògun ó
Oba omi
Sàrè ni awa sè A oyo a e de
Sàrè ni awa sè Ni géé géé odo
Oguera Ojinjé
Oguera Orisá
************************
ORIN TI BARU
(ILU)
Ke e ke e Oba toro Barú le jo
Aman Ju Obá toro Baru le jo
Ke e ke e Oba toro Barú le jo
Aman Ju Obá toro Baru le jo
************************
Ke e ke e bo Iroko
Iroko i ti ti
Dupe alado iroko
Iroko ba Ken ken
************************
Egbon mi ti e
Bará bará exu awo
Egbon mi ti e
Bará bará baru awo
************************
(ALUJA)
Barú de sobo àdá
Se ké èré, se ké èré
De sobo àdá
************************
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
Gen gen gen Oba sà rewá Baru je je
************************
Baru lò baru lò baru lò
Mo pwe
Baru lò baru lò baru lò
Mo pwe
************************
Àdá baru
Àdá baru ada
************************
Àdá baru
Àdá baru leko
************************
Àdá baru
Àdá baru lepe
************************
Baru le ko
Baru le ko awo
************************
Xango aro moro ba dupé
Xango aro moro ba dupé
Baru oyo moro ba dupé
Baru oyo moro ba dupé
**********************
Esu a Laroye Esu
kin kin kin
**********************
ORIN TI AYRA
(ILU)
O nire
Awa dode eru jee jee
Ayra igbonan a wa je lo
Ayra dode eru jee jee
Olo ripe
************************
Àyra dá kéké sòrò
Olúwaami so mòn mòn intilé.
Òrìsà kíní sé réwà a yírà,
Ayírà aiyé
************************
Osi, è ba da ayra
Ayra osi be re ko
************************
A sìn e doba àrá,
Àrá yìí ló síbè ènyin
************************
Ayra, ayra, ayra
Omo n’le, ayra mo n’lè
************************
Ayra loke bayami, manja oro
Ayra, Ayra
************************
Ayra, i ra omo n’le,
Ayra mo n’le
************************
Aira òjo
Mó péré sè, A mó péré sè
************************
Ayra Intile,
No Ko'oju ko po po le rê
Ni ko'oju Ko pó pó lê re
Ni ko'oju Ko pó pó lê re
************************
Ayra ó lè lè
A ire ò lè lè
Ayra ó lè lè
A ire ò lè lè
************************
(ALUJA)
Ayra ba i mode
Ayra ba i mode
Omo a ayra i mode
Omo a ayra i mode
************************
Iroko me fara pa bo
Iroko me fara pa bo
Ayra mode be mi o
************************
Ayra forican be fun o
Ayra forican imole
Ayra lo ijoyé
Ayra lo ijoyé igbonan
************************
(ADAHUN)
Ogum ala rá o
Mó de in ma de odo
Ayra irunmole Obanise
Kìni na irá
************************
Made ola oman da more
Made owo oman da more
Bi oman da lade
wara o da lewi
Bi oman da lade
Bi ti pa oro ni o … ako vi tare
wara wara bi more
wara wara bi more ako vi tare
************************
Ayra pá de
Ayra pá de
Ayra, Ayra
Ayra pá de
************************
Loko me fara pabo
Loko me fara pabo
Ayra mó Je
Loko me fara pabo
************************
Ayra ó, ore gédé pa,
Ore gédé ( àwa)
Ayra ó, adjaosi pa...
Adjaosi
Ayra ó, ebora pa...
Ebora
ORIN TI GBADÉ
(BATA)
Hevioso Gbade zo'ro
Ava ode Gbade zo'ro
************************
Gama ode Gbade o gama
Gama Ode
(HAMUNHA)
A run di Gbade kota de
A run di Gbade kota de
A run di Gbade kota de
A run di Gbade kota de
************************
(SATO)
Wodun Gbadé ni kaiá
Wodun Gbadé ni kaiá
Wodun Gbadé ni kaiá
Wodun Gbadé ni kaiá
************************
Gbadé zo’lo di mafa
Gbadé zo’lo di mafa
Wodun zo, zo’ro di mafa
Wodun zo, zo’ro di mafa
************************
(SATO)
Pa din din sogbo nunde
Ta nu aze bawila
Pa din din sogbo nunde
Ta nu aze bawila
************************
Bawila, bawila,
bawila bawila se
Bawila, bawila
Bawila e wodun ma do bé
************************
Sogboadan vani a pao
Sogboadan vani a pao
************************
Sogbo e e e, Sogbo e e e
Sogboadan vani a pao
************************
Xaxará xará run dere ce
Run derere navi awe
Run derere navi awe
Sogbo u’nde navi awe lo
************************
Soboadã tany avalú
Soboadã tany avalú
Arayè è è è
Arayè è è è
Soboadã tany avalú
************************