ORIN TI YEWA
Riró - (doçura, brandura)
(ILU)
Iyewa iyewa ma ajo iyewa iyewa
Iyewa iyewa ma ajo iyewa iyewa
Ma o ma o lesse
Iyewa iyewa ma ajo iyewa iyewa
************************
Iyewa iyewa ma ajo iyewa iyewa
Iyewa iyewa ma ajo iyewa iyewa
Oro um maba um lesse
Iyewa iyewa ma ajo iyewa iyewa
************************
Iyewa Iyewa le gue be
Iyewa Iyewa le gue be
Iyewa Iyewa le gue be
Iyewa Iyewa le gue be
Ayaba a un ko ki awo
Iyewa Iyewa le gue be
************************
Iyewa maasa un, o maasa
A mu re’le o
Iyewa maasa un, o maasa
A mu re’le
************************
Aara mi fá totó logbe wa e
Oluwaye
Aara mi fá totó logbe wa e
Oluwaye
************************
Aara mi fá totó logbe wa iyaba
E olo bi aiye
Aara mi fá totó logbe wa iyaba
E olo bi aiye
************************
Oro ni, E mi ko’si yéyé
Oro ni, E mi ko’si yéyé
Oro ni, E mi ko’si yéyé
Oro ni, E mi ko’si yéyé
************************
Sè ke sè dà
Iyewa iyewa ejo iyewa
Sè ke sè dà
Iyewa iyewa ejo iyewa
************************
Iyewa iyewa oni ofere
Iyewa iyewa oni ofere o
************************
Olorokun fi ewe
Ara fibo ia móré
Olorokun fi ewe
Ara fibo ia móré
************************
Iyewa le in aka mo more
Iyewa a beere o
************************
We re mi ko l’eware
Looro kufa lo xen xen
************************
Iyewa nini agba wure o
Oni tô tô ewa tô Ju a inse kwe a iyagba, oluaye
************************
Ewa ni'le moyo
Ewa ni'le moyo
E le sa, e lê sa koja dere
E le sa, e lê sa koja soba
Oni popo ye
Oni popo ye
************************
Iyewa in, xe xe in xe xe
Iyewa in, xe xe in xe xe
Ala maasa osi labure
Iyewa in, xe xe in xe xe
***********************
Mala mala oli lo ja
Mala mala oli lo ja
Oni a e o tin tin
Oni a e o tin tin
************************
Iyewa le wi
Iyewa le wi o berio omon
Iyewa le wi
Iyewa le wi o berio omon
************************
Iyewa le wi o bere o
A e a ka more
Iyewa le wi o bere a
A e a ka more
************************
A bi omon lo ju
A bi omon lewi
Lewi lewi olo ju
A bi omon lewi
************************
(ADABI)
Iyewa Iyewa, Iyewa i jo
Ta ni possi re mi Arakole
************************
Àsé sé n’eiyn,
Obe ri omon
Àsé sé n’eiyn,
Obe ri omon
************************
Iya to loode,
Àsé rì omon
Iya to loode,
Àsé rì omon
************************
Iyewa da maada
Àsé sé n’eiyn
Iyewa da maada
Àsé sé n’eiyn
************************
Aso ro kun,
ta ni ko’si yéyé
Aso ro kun,
ta ni ko’si yéyé
************************
(ADAHUM)
Iyewa fa mu ra mu ra mege,
Iyewa ta fa
Iyewa fa mu ra mu ra mege,
Iyewa ta fa
************************
Oni pe ti ti le jua
Oni ta fa ode
Oni pe ti ti le jua
Oni ta fa ode
************************
Iyewa Iyewa Fáárà fáárà oji
Gaaru gaaru
Iyewa Iyewa Fáárà fáárà oji
Ode taa fa
************************
A un’ko Iyewa Iyewa
Orin Ode o
A un’ko Iyewa Iyewa
Orin Ode o
************************
Si lo’do i e l’ogun l’ode
l’ogun l’ode
************************
Fa re’wa
ode ta fa
Fa re’wa
ode ta fa
************************
Ta no Obi o
Ta no Obi oro
Araka
Ta no Obi Oro
************************
(SATO)
Aje tolá lo kua e
Aje tola lo kua e
Eie umbo eie omã
Eie umbo eie omã
Iyewa lofi mi
Iyewa lofi mi
Iyewa lofi mi lokuae
************************
Ibalá e beru iyewa
Ibalá beru olo mi
Ibalá esó laiye
Ibalá e gan iya
***********************
To zan na, ta la de o na re
To zan na, ta la de o na re
Dan ido iro li na to zan na
Ta la de o na re minado
***********************
Ta kwe re ta
Ta kwe re sa
O zan na re vodun arawa
S’ogun rumbena vodun
***********************
Nibo nibo me hunto
Iyewa, Iyewa
Nibo nibo me hunto
Iyewa, araka
***********************
Iyewa le wa ze
Iyewa le wa ze
Dahome a gaya vodun
Dahome a gaya vodun
***********************
Savulu kwe humbono
Savalu kwe ma die
***********************
È é é le gue jo, ara in le gue jo
È é é le gue jo,
È é é le gue jo, ara in le gue jo
È é é le gue jo,
************************
Mire mire mi a to mire
Mire mire mi a to mire
Mire mire mi a to, Mire mire mi a to
Mire mire mi a to mire
************************
(BRAVUM)
Bo ina Tíí dan
Tíí dan a dà na dan
************************
To zala, to zala na ge bo
To zala iyewa bessen, to zala na ge bo
************************
Iyewa die,
Oni agbo lo de
A izo di le,
Oni agbo lo de
************************
N’ile we, N’ile we
Da ni apa do
Vodun Iyewa, ma de Iyewa
Da ni apa do
************************
Mabo mabo, mabo do i do do
Mabo mabo, mabo do i do do
Mabo mabo, mabo do i do do
Mabo mabo, mabo do i do do
Iyewa gui die àsé bere ee
Iyewa gui die àsé bere ee
Iyewa gui die àsé bere ee
Iyewa gui die àsé bere ee
************************
Iya ma’de si ma de in, ma devo
Iya ma’de si ma de in, ma devo
Iya ma’de si ma de in, ma devo
Iya ma’de si ma de in, ma devo
************************
Iyewa ku le, si a ma devo
Iyewa ku le, si a ma devo
************************
Gaaru, gaaru
Beere
Gaaru, gaaru
Beere
************************
O fuuro, iyewa fuuro, beere kwe
O fuuro, iyewa fuuro, beere kwe
Ahum me si, o fuuro, e ma devo be un kwe
Ahum me si, o fuuro, e ma devo be un kwe
************************
(HAMUNHA)
Fe re re to bi odo
Fe re re to bi odo
Fe re re to bi odo
Fe re re to bi odo
************************
Iyewa mi fa to pa n’ile wa
Oluwaye
Iyewa mi fa to pa n’ile wa
Oluwaye
************************
Cole Cole baara ko ro
Cole cole Baraja
************************
Beere o beere bere o
Iyewa beere o
Beere o beere bere o
Iyewa beere o
************************
Iyewa faara dide
Rin ro
Iyewa faara dide
Rin ro
************************
(KORIN EWE)
Ogue re le bo iza, ba la o
Ogue re le iza, o o
Ogue re le bo iza, ba la o
Ogue re le iza, o o
E bo iza o
O beere o
E bo iza o
O beere o
************************
Ogue re re sa ro ro
O guere ba ra ko ba o
Bara ko idan
O guere bara ko idan
************************
Fè rèéré do ri sà n'ló
Fè rèéré do ri sà n'ló