ORIN TI OMOLU
Atótóo! (Silencio!)
Omolú olúké a ji béèrù sápadà!
(ILU)
Ó táálá bé okùnrin wa ki lo kun,
Táálá bé okùnrin.
Abénilórí ìbé rí ó ní je oluwàiyé táálá bé okùnrin.
Ó ní a ló ìjeníìya
Ajàgun tó ló ìjeníìyà olúwáiyé. Táálá bé okùnrin
*********************
Ó ìjeníìyà bàbá
A sìn e gbogbo wa lé.
Ó ìjeníìyà bàbá
A sìn e gbogbo wa lé ó
*********************
Ijí, Dàgòlóònòn kí wa sawo orò.
Dàgò ilé ilé,
Dàgòlóònòn kí wa sawo orò
*********************
Agba in agba ole
Fáárà fáárà fáárà odi
Agba in agba ole
Fáárà fáárà fáárà odi
*********************
Ó àjerín l'ònòn lóòde bá ìwà ó bò-m-bàtà.
Aé lóòde bá ìwà ó bò-m-bàtà
*********************
Opé ire.
Onílè wà àwa lésè òrìsà,
Opé ire.
E kòlòbó e kòlòbó sín sín,
Sín sín kò,
Sin sín kò, Kòlòbó e kòlòbó sín sín
sín sín kò,
*********************
E njí omolú tó
Gbèlé gbèlé mi báa yí lówó.
Ó jé ji àwúre
Gbèlé gbèlé mi báa yí lówó.
*********************
E ló e ló e kun
omolú tó ló kun eron ènìòn
*********************
Omolú pwè olóre
A àwúre e kú àbò
Omolú pwè olóre
A àwúre e kú àbò
*********************
Omolú sóbóló ojú wa ó nòn wa le jé ni fojúrí
*********************
Omolú pè a júbà a èkó,
Oníyè.
Omolú aráayé pè a júbà a èko.
Oníyè,
Omolú pè a júbà a èkó oníyè
*********************
Oníyè tó gígbón
Jé a npenpe
E ló. Gbè wàiyé tó ní gbón,
Jé npepe.
Omolú wàiyé tó ní gbón
*********************
Ó kíní gbè fáárà faroti,
Ó kíní gbè fáárà. Àfaradà,
Oní pópó oníyè,
Kíní ìyà wa fáárà. Àfaradà
*********************
Ó gbélé iko
Sàlà rè sàlà rè lórí
*********************
Ó àfomó ó fá ojú rè mò fá,
Aráayé njó jó
Aráayé njó n’le
Aráayé njó jó
*********************
Wúlò ní wúlò,
Ase lè gbèlé ibè kò
*********************
E ofarajo oni sá we le
Jé jé gbale
Ofarajo oni sá we re
Je je gbale
*********************
Olórí ìjeníìyà a pàdé
olórí pa,
*********************
A bàbá òrun mó fé,
A bàbá òrun e njó jó
*********************
Iji Oluwaye, Aba iko, Afomon aba iko
Aba iko, Afomon aba iko
*********************
Jó a lé ijó,
É jó a lé ijó,
É jó a lé ijó.
Àfaradà a lé njó ó ngbèlé
*********************
*********************
*********************
(IGBYN)
A jí nsùn aráayé ó ló ìjeníìyà
E wa ká lo.
Sápadà aráayé ló ìjeníìyà
E wa ká lo
Ìjeníìyà. Aráayé, é ajeniníìyá, ajeniníìyá,
Àgó ajeniníìyá. Máàa ká lo ajeniníìyá
*********************
(HAMUNHA)
Àgò jó ilé
Omo omolú jó,
Àgò jó ilé.
Omo omolú jó àgò jó ilé
*********************
Elé fúló àiyé
Elé fúló a lè inón.
Elé fúló a jí n’sún
Elé fúló ajagùnnón
*********************
Fa’ra fa’ra fa’ro ji
Omolu akara ó
Fa’ra fa’ra fa’ro ji
Omolu akara ó
*********************
Iji bara loko
Iji bara loko pá jue
Bara loko pá jue
Bara loko omolu arawe
Pájueti tu e pá jue, omolu arawe
Pájueti tu e pá jue, omolu arawe
*********************
Àká ki fàbò wíwà.
Àká ki fàbò wíwà.
Àká ki fàbò wíwà.
Àká ki fàbò wíwà.
Wáá kolé, wáa kolé sé awo orò
Wáá kolé, wáa kolé sé awo orò
*********************
Sá-sá wa òrò fún awo,
Gbalé gbalé
*********************
Sá-sá wa òrò fún awo,
Sá-sá wa òrò
*********************
N’he ori n’dà
Ajagùnnón ori n’dà
N’he ori n’dà
Ajagùnnón ori n’dà
*********************
Àgó omolu já
Ko loorí a bere ko
Àgó omolu já
Ko loorí a bere ko
*********************
Mo in mo in l’ase
ase morio owo
*********************
E lê já oniumba jagun la oniumba
E lê já oniumba jagun la oniumba
*********************
Kíní a awo ó ní kójó,
Jé ó ngbélè.
Ki wa jó e ki wa jó ó ní kójó,
Jí ngbélè ki wa jó
*********************
(EGO)
Aráayé a je nbo,
Olúgbàje a je nbo
*********************
(OPANIJE)
Go ro go ro
go ro go ro
sa hun
sa huni kota
sa hunde
*********************
Opa ni jéé
Opa ni jéé
Opa ni jéé odo
*********************
(cantiga para subir)
(ILU)
Oro la bamba
Oro la bamba
(HAMUNHA)
Sé ó gbèje
Kóró nló awo,
Kóró nló awo,
ORIN TI OLÚGBÀJE
Aráayé a je nbo , Olúbàje a je nbo
Aráayé a je nbo , Olúbàje a je nbo
************************
(REZA)
È é é ajeniníiyá, ajeniníiyá
Àgò ajeniníiyá
Máà kà lo, ajeniníiyá,
Ajínsùn aráaye, ó ló ìjeniníiyá
E wa ká ló
Sápadà aráaye, ló ìjeniníiyá,
E wa ká ló
Ìjeniníiyá aráaye
************************
Opeèré má dó péré
Ó bèré ké se
Má dó há, má dó pèré
Opeèré má dó péré
Ó bèré ké se
Má dó há, má dó pèré
Don hòn há,
Don hòn há é à , Empé
Don hòn há
Opèré má dó péré
Dó sú, màá dó é
Dó sú, màá dó ,
Dó sú, màá dó
Dó sú, màá má n’gbé
Ayò kégbe hún hún
Ayò kégbe hún hún
************************
(ILU)
Omolú Kíí bèrú já
Kòlòbó se a je nbo
Kòlòbó se a je nbo
Kòlòbó se a je nbo
Aráayé.
************************
(BATA)
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Sápadà , A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Ajunsú , A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Omolu, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
obalúwàiye , A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Ajagun , A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Azouane, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Afoman, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Arinwarun, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Arawe, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Avimaje, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Afenan, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
intòtò, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Agbagda, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Jagu Jaguna, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Posun, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Savalu, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
Ágò n’ilé , n’ilé
N’ilé ma dàgó
Etetu, A jí nsún , Ma dàgó
Ágò n’ilé ágò.
************************
(ILU)
Ó gbélé ìko , sàlàrè
Sálà rè lórí
Ó gbélé ìko , sàlàrè
Sálà rè lórí
************************
Olórí ìjeníiyà a pàdé
Olorí pa
Olórí ìjeníiyà a pàdé
Olorí pa
************************
Jó alé ijó , é
Jó alé ijó , é jó
alé ijó,
Àfaradà a lé njó ó ngbèlé
************************
(HAMUNHA)
Àká ki fàbò wíwà
Àká ki fàbò wíwà
Wáá kalé , wáá Kalé sé awo orò
Wáá kalé , wáá Kalé sé awo orò
************************
Ò kíní gbé fáárà farotì
Ò kíní gbé fáárà àfaradà
Oní pópó oníyè
Kíní ìyìyá wa ìfaradá
************************
(ILU)
Ó táálá bé okùnrin wa ki lo kun,
Táálá bé okùnrin.
Abénilórí ìbé rí ó ní je oluwàiyé táálá bé okùnrin.
Ó ní a ló ìjeníìya
Ajàgun tó ló ìjeníìyà olúwáiyé. Táálá bé okùnrin
************************
Wúlò ní wúlò,
Ase lè gbèlé ibè kò
************************
E ló e ló e kun
omolú tó ló kun eron ènìòn
************************
Onílè wà àwa lésè òrìsà,
Opé ire.
E kòlòbó e kòlòbó sín sín,
E kòlòbó e kòlòbó sín sín,
Sín sín kò,
Kòlòbó e kòlòbó sín sín
sín sín kò,
************************
Omolú pè olóre
A àwúre e kú àbò
************************
Oníyè tó gígbón
Jé a npenpe
E ló. Gbè wàiyé tó ní gbón,
Jé npepe.
Omolú wàiyé tó ní gbón
************************
(SUBIR)
(HAMUNHA)
Sé ó gbèje
Kóró nló awo,
Kóró nló awo,
*********************
(ÒSÙMÀRÈ)
(ILU)
Lé'lé mo rí ó ràbàtà,
Lé'lé mo rí òsùmàrè ó. Òsùmàrè wàlé'lé mo rí òsùmàrè
************************
Aláàkòró lé èmi ô
Aláàkòró lé ìwo
Aláàkòró lé èmi ô
Aláàkòró lé ìwo
************************
Òsùmàrè
Ó ta kéré,
Ta kéré,
Ó ta kéré
************************
(NÀNÀ)
(ILU)
Òdì nàná ní ewà,
Léwà léwà e
Òdì nàná ní ewà,
Léwà léwà e
************************
Nàná ayò
Odi nàná ayò ol’ódo,
Nàná ayò
Odi nàná ayò ol’ódo,
************************
Ò ìyá wa òré
Ò ni aijalò
Ò ìyá wa òré
Ò ni aijalòòde
************************
(IYEMANJA)
(BATA)
Àwa ààbò a yó
Yemonja àwa ààbò a yó. Yemonja
************************
Ìyáàgbà ó dé ire sé
A kíì é yemonja.
A koko pè ilé gbè a ó yó
Ó fí a sà. Wè rè ó
************************
À sà wè lé,
A sà wè lé ó odò fí ó
A sà wè lé
************************
Ìyá kòròba
Ó kòròba ní sábà
************************
(OYA)
(ILU)
Oya gbàle láárí ó, oya gable
Oya gbàle láárí ó, oya gable
Àdá máà dé f’ara gambele
Oya gbàle láárí ó, oya gable
************************
Ó ní laba-lábá, ó lábá ó,
Ó laba-lába, ó lábá ó
************************
Olúa féé fé Sorí omon,
Olúa féé fé Sorí omon
************************
(quartinha)
Ó na pa ki n’há
Gbálè
************************
(ÒÒSÀÀLÀ)
(IGBIN)
Èyin rí àwa
Ìgbàgbó wa okòn
Èyin rí àwa.
Ìgbàgbó wa okòn,
Ètùtù sé ipàdè siré,
Kò rú lé.
Kò rú lé bàbá Ifá,
Kò rú lé kò rú lé bàbá Ifá.
Kò rú lé ò rú lé bàbá. Ifá
Kò rú lé kò rú lé bàbá Ifá
************************
Àjàlá mo rí mo rí mo yo
Álá forí kòn
E àgó fi rí mi
************************
Bée orí kò kíì Àjàlá
bàbá òkè
kí a mò rè. Kíì Àjàlá,
bée orí kò
************************
(IJESA)
Ojo mò tyìn odó aláyé ojó,
Ojó bí walé ojó.
Ojo mò tyìn odó aláyé ojó,
A bo wa bàbá ó