ORIN TI ÒSÚN
Òóré Yéyé ó! fí dé ri omon
Òóré Yéyé ó!
16(Salve a Senhora da bondade!)
(ILU)
Yèyé yèyé yèyé ó ó
Oro miywa nu ase to ri efon
Yabakoju iyaba o
Oro miywa nu ase to ri efon
************************
O ni iya beere
O ni iya beere o
O ni iya beere o
Òsún ade omo wa
************************
E fibò
E fibò dò wa iya Òsún
************************
Ayaba gèdègé sé rè egé
Ayaba gèdègé sé rè egé
************************
Iya omi ni ibu
Odòomi rò òrìsà ó yèyé
Iya omi ni ibu
Odòomi rò òrìsà ó yèyé
************************
A yin mà yin mà
Kéé-kéé òsú omi s'orò odò
A yin mà yin mà
Kéé-kéé òsú omi s'orò odò
************************
Maabó ya, iya bo iya
Maabó ya, iya bo iya
Omi s’àsé ó omi ni ibu
Iya bo iya, iya bo iya
************************
Omi fa were, Omi fa were omi rò
Iya Omi ta we se
Omi fa were, Omi fa were omi rò
Iya Omi ta we se
Òsún ki ba lade
Omi fa were, Omi fa were omi rò
Iya Omi ta we se
************************
Aka murele òsún fara aajà
Murele o l’òsún
Aka murele òsún fara aajà
Murele o l’òsún
************************
A mú iyan mú iyan ojare
Elemoso tori efon
************************
K'omo l'odò won sì e
K'omo l'odò won òpò
A e fé a e fé
Àwa yìn sìn sìn
************************
Odé pasí lo tu bì omón
Moyo dindin omo r’eja
Moyo bi olè
Moyo, moyo bi olè, moyo
Moyo dindin omo eja
Moyo, moyo bi olè, moyo
Moyo dindin omo eja
************************
La mu ra
La mu ra odo bi yeye
La mu ra odo l’Òsún
La mu ra odo bi yeye
************************
Ebo re mi afere Miywa
Ase gbogbo
Ebo re mi afere Miywa
Ase gbogbo
ki ni je, ki ni je, ki ni je, ki ni ja,
Ase gbogbo
ki ni je, ki ni je, ki ni je, ki ni ja,
Ase gbogbo
************************
(KORIN EWE)
Omi ò táála de
Omi ò táála de o merin
************************
Òsún e loolá
Imole lóomi
Òsún e loolá iyaba
Imole lóomi
************************
Yèyé yèyé yèyé
Olomi o
Yèyé yèyé yèyé
Olo re
************************
A dò sì màa gbe iyá ara oro
A dò sì màa gbe iyá ara oro
************************
A laba laba da òsún
A laba laba da òsún
************************
Ìyá omi imonlè nì ew´w awo
Ìyá omi imonlè ásèki obèewé
Ìyá omi imonlè nì ew´w awo
Ìyà omi imonlè àsèki omon:
Ojù odò àsèki ojù oró
Òsibàtà oró olóòké
Omi olóomi ayé àsèki omon
************************
(ALUJA)
Yèyé mure jo
Jin gue le, jin gue le, mure jo
Yèyé mure jo
Jin gue le, jin gue le, mure jo
************************
Yèyé mure jo
Jin guele, jin guele ofa bebé
************************
Wara wara e
Male male odo
Àsé Òsún male
Male male odo
************************
(BRAVUN)
A munha, munha ofa abebe sooro
Ofa abebe
A munha, munha ofa abebe sooro
Ofa abebe
************************
(ADAHUN)
A ijo e lê um si si
Ofa mi rewe
************************
Ofa n'le kwe maabo ya
Mas no ya rô ko
************************
Ofa n'le kwe
Ofa n'le kwe Òsún
************************
Iyalode Osogbo
Iyalode Igesa
************************
Iyalode Opara
Iyalode Iponda
************************
Òsún Osogbo ode n'la
Òsún Osogbo ode n'la
************************
Awa se’n alode
Awa se’n alode
Rewe rewe rewe
Awa se’n alode
************************
Ki l’ose mi iponda
Ki l’ose mi òpàrà
Rewe rewe rewe
Ki l’ose mi òpàrá
************************
Ofa abebe sooro
Ofa abebe sooro
Rewe rewe rewe
Ofa abebe sooro
************************
A é é òpàrà
Òpàrà ko ta meje
************************
A é é òpàrà
Òpàrà fàári Odé
************************
A ijo é é é
A ijo k'ode lo mó
************************
(IJESA)
Awa oro,
Awa oro
Olorun ale ise ara oro
Olorun morio
************************
O oro
E ma ku oro
E ma ku oro
E ma ku oro efon
************************
Yèyé yèyé olóo odó
Iya mi yèyé
A òsún ko mù abò
A awa sirè sà sà
************************
Ayaba òrun omon fè
Fèe èe èmi ó
Ayaba òrun omon fè
Fèe èe èmi ó
************************
Ijesa mo rì bo òun ijesa
Ijesa mo rì bo òun ijesa
************************
Yèyé yèyé
Yèyé yèyé yèyé s’orò odo
Yèyé yèyé
Yèyé yèyé yèyé s’orò odo
E n’ma s’orò, mà fè fè s’orò odo
Yèyé yèyé
Yèyé yèyé yèyé s’orò odo
************************
Yèyé mi ma oro
Irumole Yèyé
Ìyá ìmálè odó,
Òrún wa n'ilé òdó
A e èkó, A e egé
Iyalòóde iya awo oró
Òrún ó yè yé o
Ìyá ìmálè odó,
Òsún wa n'ilé òpó
************************
Yèyé yèyé mi ma oro
O yèyé oro
O yèyé oro
Yèyé yèyé mi ma oro
O yèyé oro
O yèyé oro
************************
Lo ja ma tin do la’ya, lo ja
Òsún kare
Lo ja ma tin do la’ya, lo ja
Òsún miywa
Lo ja ma tin do la’ya, lo ja
Òsún Opara
Lo ja ma tin do la’ya, lo ja
Òsún Ajagura
Lo ja ma tin do la’ya, lo ja
Òsún Iponda
************************
Iya mi, Òsún Miyuá
Agba n’ile àsé igená
Iya mi, Òsún Miyuá
Agba n’ile àsé igená
************************
Omi mo re wa, Omi mo re wa
K’oro oro Òsún mi logun baba dero
Omi mo re wa, Omi mo re wa
K’oro oro Òsún mi logun baba dero
Fa ri a de mo i’roko, baba la wure
Fa ri a de mo i’roko, baba la Okan
************************
A e fé, a e fé, àwa yìn sìn sìn
A e fé, a e fé, àwa yìn sìn sìn
************************
Iyaloode iyaloode iya o
Iyaloode iyaloode iya o
************************
Ìyálóòde ìyálóòde ìyá ó.
E ìyalóòde ìyá l'omi òrun ayè ó,
Ìyalóòde ìyá.
Olómi ayè ó yèyé ó
************************
Yèyé yèyé oke ó
Yèyé yèyé oke ó
Òrun ala mo ifá
Òsún a ko mù abò
Òrun ala mo ifá
Òsún a ko mù abò
************************
Yèyé yèyé oke ó
Yèyé yèyé oke ó
Ayra la fo npa ó
Òlóo mo ke wa po
Afofo la po nise
Ori omo ke wa po
************************
Léwà léwà lé
Òsun a dé àwa omi sé orò
************************
Olóomi máà
Olóomi máà iyó
Olóomi máà iyó
Abado ora yèyé ó
************************
A iya òsún
Òsún mi re re o
A iya òsún
Òsún mi re re o
************************
A yèyé so ojú gbale iso
So ojú gbale
A yèyé so ojú gbale iso
So ojú gbale
************************
Iso, iso so ojú gbale
Iso, iso so ojú gbale
************************
Labure o yèyé omolocum owo
alabawo awade omorode
Labure o yèyé omolocum owo
alabawo awade omorode
************************
Labure ki mi ka odo
Labure
Labure ki mi ka odo
Labure
************************
Olu we kinije kare le lodo
Kare
Oluaywe kinije kare le lodo
Kare
Òsún de, kare
Òsún de, kare
Òsún de, kare
Òsún de, kare
Òsún de kare
Kare ijesa
Òsún de kare
Kare iya mà
************************
A iso layo
Odara k’oba layo
************************
Ó yèyé omi ní ibú,
Aláadé ìrúnmonlè
************************
E ìrúnmonlé ayaba e kú àbò
Omi ayè sé
************************
Rora yèyé ó omi aso re re
Rora yèyé ó omi aso re re
************************
(ILU)
Iyaba ki mì jó ba jó ba murele
Kimi jó ba ó
************************
(IJESA)
Sa wele pa mi nlo
Sa wele pa mi nlo
Sa wele yẹ yẹ o
Sa wele pa mi nlo
ORIN TI RODA TI ÓSÚN
(BATA)
Sin da lo kwe lo ye
Sin da lo kwe ka ma wa sooro
Ala ojo n’le wa o
Ala ojo n’le wa o
************************
Òóré Yéyé
Òóré Yéyé ó!
Òóré Yéyé
Òóré Yéyé ó!
************************
Òsún kare
Òsún Iponda
Òsún Opara
************************
Iponda n’le Òsún
Iponda n’le Òsún olore
Opara n’le Òsún
Opara n’le Òsún olore
Miywa n’le Òsún
Miywa n’le Òsún olore
Kare n’le Òsún
Kare n’le Òsún olore
************************
O wuro were
Were were o wuro were
O wuro were
Were were o wuro were
************************
Pè r’omi abèbè Òsún
Pè r’omi abèbè Eléèdá
Pè r’omi abèbè Òsún
Pè r’omi abèbè Eléèdá
Ìyá Ijùmu ta k’ara Eléèdá
Pè r’omi abèbè Òsún
************************
A rí be dé o, omi´rò
A arà wa, omì’rò
A rí be dé o, omi´rò
A arà wa, omì’rò
************************
Omi ní wè náà Òsún
Omi ní wè
Omi ní wè náà Òsún
Omi ní wè
Séké-séké náà dò ojú
Máà ojú omi ní wé olówó.
************************
Igbá wo wo, Igbá si Òsún màá réwà
Igbá wo wo, Igbá si Òsún màá réwà
Àwá sìn e, ki igba réwà,
Igbá wo wo, Igbá si Òsún màá réwà
************************
Òsún ìyá mi ó,
Òsún t´olà ní’mo bi
Òsún ìyá mi ó,
Òsún t´olà ní’mo bi
Olúwà odò jékí l’ayó,
A l’omo, wa ni ire
Olúwà odò jékí l’ayó,
A l’omo, wa ni ire
************************
(IJESA)
Àwa omo oló orò dé o, á dé é o.
Àwa ló máa l’orò ilé wa ó, á dé é o.
Àwa, àwa omo ìjèsà.
Àwa omodé ibè ó
************************
Ó Yèyé Olòrìsà Karè gbogbo..Karè
Ó Yèyé Olòrìsà Karè ìjèsà ... Karè
Ó Yèyé Olòrìsà Karè gbogbo..Karè
Ó Yèyé Olòrìsà Karè ìjèsà ... Karè
Òsún dé, karè
Òsún dé, karè
Òsún dé, karè
Ó Yèyé Olòrìsà Karè gbogbo..Karè
Ó Yèyé Olòrìsà Karè ìjèsà ... Karè
Òsún dé Karè, karè ìjèsà
Òsún dé Karè, karè omo
Òsún dé Karè, karè nílé
Òsún dé Karè, karè ìjèsà
************************
A e èkó
A e egé
Iyalòóde iya awo oró
Òrún ó yèyé o
Ìyá ìmálè odó,
Òsún wa ilé òpó
************************
A e fé, a e fé, àwa yìn sìn sìn
A e fé, a e fé, àwa yìn sìn sìn
************************
Olóomi máà
Olóomi máà iyó
Olóomi máà iyó
Abado ora yèyé ó
************************