ORIN TI NÀNÁ
Sálùbá nàná burúkú!
(Nos refugiaremos com nàná da morte ruim!)
Sálùbá nàná (Nos refugiaremos com nàná)
(ILU)
Nàná léwà o
Odara o lowo se se
Nàná léwà o
Odara o lowo se se
************************
Sà ra o nàná oluwodo
Ki ni odo
Sà ra o oluwodo
Se se
************************
Sà ra odi nàná ayò,
Olobi inà, inà odo
Sà ra odi nàná ayò,
Olobi inà, inà odo
************************
A mù n’há, mù n’há
Já ke zo
A mù n’há, mù n’há
Já ke zo
************************
Òdì nàná ní ewà,
Léwà léwà e
Òdì nàná ní ewà,
Léwà léwà e
************************
Nàná ikú rè
Omon nílè kò ràjò,
Kò ràjò, kò rajò,
Ó félé lé , kò ràjò
************************
Nàná ayò
Odi nàná ayò ol’ódo,
Nàná ayò
Odi nàná ayò ol’ódo,
************************
Ó ibin rìn sá-sá ra,
Ó ibin rìn sá-sá ra,
Òdì nàná ayò,
Nàná ayò olùwodò sésé
************************
Ò ìyá wa òré
Ò ni aijalò
Ò ìyá wa òré
Ò ni aijalòòde
************************
Ó ìyá wa òré
O ni as le jua
Ko le, ko le
O ni as le jua
O ni as le jua
Ko le, ko le
O ni as le jua
O ni as le jua
************************
Oluo tala wajo
Oluo to te wajo
Tala wajo
Oluo to te wajo
************************
(HUNTO)
Nana buruku no kwo
Nana buruku no kwo
Nana buruku no kwo
Nana buruku no kwo
************************
(KORIN EWE)
E tí mòn sòn fún omoode,
E tí mòn jé ó
************************
Ó ìyá
Àbíkú ó,
************************
E àbíkú olóyéyè.
Nyin won yèyé,
Olóyíyè
Nyin won yèyé
************************
(ADAHUN)
E nàná olúwàiye e pa e pa
E nàná olúwàiye e pa e pa
************************
E taláàyà àjò
Olúwodò ki wa àjò
************************
(BATA)
E e ji lo igbyn si e ko fun mi
Oko a e, ire a irece
E e ji lo igbyn si e ko fun mi
Oko a e, ire a irece
************************
Iyaba ki mì jó ba jó ba murele
Kimi jó ba ó