ORIN TI LÒGÚN EDE
Loci-loci logun
(Brada, principe guerreiro)
(BATA)
Lóòtun l’ààbò,
Igbó òrìsà a kofà awo
Lóòtun l’ààbò,
Igbó òrìsà a kofà awo
**********************
Oníigbó olódò
Wà nilé oníigbó olódò
Wà nilé
************************
Olóode pa eron olóodò epeja
Oba omi níìbú
Olóode pa eron aláamòn òrìsà
************************
Akofà àgò òrìsà igbó
Ode àáròlé o
Àáròlé ó òrìsà ode
Ode ní ó òrìsà igbó
************************
(KORIN EWE)
Kéere-kéere ode ó,
Kéere-kéere ode ó olóòrìsà
Ké mi má sá, ké mi mò awo
Òrìsà ode igbó ótòkonsósó,
Àwa omodé ti erinlè,
Àwa omodé ti ó kú eron,
Ode igbó ti kó là,
Ode igbó ti kó là,
Bàbá ode igbó ofà
Isè isè lè sórò.
************************
Bàbá ode ewé èjè,
Bàbá ode ewé èjè
Ní igbó ní bàbá òrìsà
Ní igbó ni bàbá lògún-ode
Bàbá yìí dakójá mi ojú ààrò,
O ti kó là ase e tyìn ofà,
Bàbá igbó ode ènyin.
************************
Ó igbó ó lògún ó
A ode ki igbó ní
Ó bì igi igbó ewé
Ofà rè níigbó lògún ode,
Lògún ode,
Lògún ode
Ofà rè níigbó lògún ode
************************
(IJESA)
Lògún e pa, a mi loyo
A pere Lògún, mi loyo
Olojise, ke mi, ke mi
la ka ja, la ka ja
alagbede Ologun o
E, e, e, a n’gue le, ala oro, ala oro
E, e, e, a n’gue le, ala oro, ala oro
************************
Ifa oju yeye ibe iro
Ifa logun fa ojinse ala ru o
E a n’gue le
Ala ru o, ala ru o
E a n’gue le
Ala ru o, ala ru o
************************
Olówó
A kofà rè a kofà rè wo,
É a kofà.
Ijó ijó lógún ó é a kofà
************************
A lògún
E máà kòofà,
Ode lònòn.
E máà kòofà,
Olórí gún
E máà kòofà
************************
Aé aé ode lógún.
Ode lògún ní báàyìí.
Aé aé ode lógún.
Ode lògún làpanòn
************************
É lógún dé lé k'òkè
É é é é é,
************************
É lògún aro aro
Fáàra lògún, Fáàra lògún pa,
************************
Araka gbogbo ire o
Àiyé oba ní sà, Lògún dé é rè.
Àiyé oba ní sà, Lògún dé wa
************************
Lògún ode kò ìyà kò ìyà,
Lògún ode kò ìyà.
Ijó ijó fíríi l'àyà,
Lògún ode kò ìyà kò ìyà
************************
Lògún wa olórí,
Lògún a l'anu a ké njó
************************
Lògún ode
E un Ofá, é Lògún Oya
************************
Lògún ode
Lògún Aro
Loci Igbayn
Ode Logun afose Iroko
************************
Lògún ode
Lògún ode
E mòofà ó
Si òpó lògún ará
************************
Lògún ode
Lògún aro
Ode ba imá
Ibayn Lògún F’ara ojo
************************
Alá lá láayé é é
Ode máà nsé
************************
A e gbàyìí l'àse
Ode gbàyìí l'àse, Àiyé gbàyìí l'àse
************************
lòóro kwe
lòóro kwe
lòóro kwe
lòóro kwe re
************************
lòóro kwe
Iyami kekere
Iya bàbá lògún o
Iya máà máà sooro
************************
O Li ro wo mojinje
Lorogun Leri á
************************
Lorogun Ita we je
Obe mabje ka fi danwo
I oro Ita we je
Ode moje ka ku
I oro Ita we je
Ode moje ka ku
I oro Ita we je
Ode moje ka ku
************************
Beere beere koke mayo
Iyakooro Irumole
Iyakooro ...
Irumole
Iyakooro ...
Irumole
Iyakooro ...
Irumole
************************
Ode mo je ka kowo
Ologun mi ta we je
Ode mo je ka kowo
Ologun mi ta we je
************************
Lògún ati rò, ati rò
Lògún ati rò ijesa
************************
E alá lá àiyé àwa njéé-jèè
Ode àgbóòròn
************************
E alá lá àiyé odé baiyn sé
E alá lá àiyé
************************
Moje ka k uso dà nà
Àwó ni tauche
************************
bere bere koke ma ó
Akoro erun male
************************
O iri loke iri loke
Baba oke ee irun malé
************************
(EGO)
Lógún ibgba o
lógún de
Lógún ibgba o
lógún de
************************
Made made Ode Iya o
Made made Ode i s’òrò
************************
Ode géere a pa sawana, sawana
Ode géere a pa sawana ó ó ó
************************
Ode géere ó si Lógún
Ode géere ofá lògún ode
************************
Béere Béere a pa su wana, wana
Ode kaku ode iba ye ye o
************************
Gbàyìí l'à le nù
Gbàyìí l'à le nù
Yè yé
Gbàyìí l'à le nù
************************
Yè yé
lògún a Gbàyìí l'rà
lògún a Gbàyìí l'rà
lògún a Gbàyìí l'rà loko
************************
Ina ko de pa,
Ina ko de pa,
Bàbá sòóro
Ina ko de pa,
************************
Kéere- kéere loci loci
Kéere- kéere pa lògún ode
************************
Omolocun n’ge n’bo
Omolocum
Omolocun n’ge n’bo
Omolocum
************************
Oro ri dana, da la ri ro
Ode de
ó Ìròkò
Ode de
Ologun pa, da la ri ro
Ode de
ó Ìròkò
Ode de
************************
Lògún pa o
Olore
Lògún pa o
Olore
************************
Òóré Yéyé,
Òóré Yéyé, Òóré Yéyé
Òóré Yéyé,
Òóré Yéyé, Òóré Yéyé
************************
Pa Lògún pa, Lògún pa
Loci ya ba
Pa Lògún pa, Lògún pa
Loci ya ba
************************
I mà kode pa, i mà kode pa
Baba sooro i má kode pa
************************
(SAMBA)
Ta ó gbé la kò sé
Lògún ó
************************
A in da é Lògún ede
A in da é Lògún ede
************************
(Igesa)
Dide, dide, dide
Koke ma o, a sa oro
************************
Se kwen, Se kwen
Agba L'oye
Se kwen, Se kwen
Agba L'oye
************************
(ADAHUN)
Omorode e du ara
Omore se omo re o
Osun adola a feere o, Orixá
Omorode e du ara
************************
Oni ye, Iya sasa, iya, iya, iya
Onie Ye Iya sasa, logun ede
************************
************************
(HAMUNHA)
Pè kù o
Pè ku lè pè
Pè kù o pè kù o
Pè ku lè pè
(EGO)
Ofà ode ba yíìrá
Ó níigbó l'óodò kòkè
************************
(HAMUNHA)
Alákétu re
Sààlò ti ó dára,
Sààlò ti. Ó dára àáròlé
Sààlò ti ó dára
************************
Báàyìí láse onílá
Ó ki a bo òní
************************
Àgò lé àwa dàgòlé lé,
Àgò lé àwa dàgòlé lé
************************
Ode ó àyè
Ode ó àyè
************************
Àwa wò ode nílé wa,
Ode ki fíigbó
************************
Ó báàyìí láse omi ró,
Ode báàyìí láse miró.
************************
Láé-láé ó ni tofà dode,
Ode ni tofà
Láé-láé ó ni tofà dode,
Ode ni tofà
************************
(EGO)
Made made Ode iyawo
Made made Ode i s’òrò
************************
Ode géere a pa sawana, sawana
Ode géere a pa sawana, sawana ó
************************
Béere Béere aka kawan, wanan
Ode kakuma we awanan oo
************************
Ida go le pa, ida go lepa
A pa sòóro ida go le pa
************************
Yè yé
Gbàyìí l'à le nù
Gbàyìí l'à le nù
Gbàyìí l'à le nù
************************
Ode géere ó Ìròkò
Ode géere fàárá lògún ode
************************
Kéere- kéere loci loci
Kéere- kéere pa lògún ode
************************
Omolocun n’ge n’bo
Omolocum
Omolocun n’ge n’bo
Omolocum
************************
Oro ri dana, da la ri ro
Ode de
ó Ìròkò
Ode de
Ologun pa, da la ri ro
Ode de
ó Ìròkò
Ode de
************************
Lògún pa o
Olore
Lògún pa o
Olore
************************
Òóré Yéyé,
Òóré Yéyé, Òóré Yéyé
Òóré Yéyé,
Òóré Yéyé, Òóré Yéyé
************************
Pa Lògún pa, Lògún pa
Loci ya ba
Pa Lògún pa, Lògún pa
Loci ya ba
************************
I mà kode pa, i mà kode pa
Baba sooro i má kode pa
************************
(SAMBA)
Ofà ní ó gbé wa kòséni
Lògún ó
(Igesa)
Dide, dide, dide
Koke ma o, a sa oro
************************